Peso Argẹntínà jẹ́ owóníná ní orílẹ̀ èdè Argẹntínà pẹ̀lú àmì ìdánimọ $ tí ó máa n wà lẹ́yìn iye owó bí ó ṣe wà fún àwọn ìlú tókù tó ń lo owó dólà.
Ó pín sí ọnà ọgọ́òrún. Kóòdù ISO 4217 ẹ̀ jẹ́ ARS. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ owóníná ilẹ̀̀ Argẹntínà tí wọ́n tí ná kọjá ni woṇ́n ti pè ní "peso".
Peso Argẹntínà | |
---|---|
Peso argentino (Spanish) | |
ISO 4217 code | ARS |
Central bank | Central Bank of the Republic of Argentina |
Website | [http://bcra.gov.ar bcra.gov.ar] |
User(s) | Argentina |
Inflation | 26 % estimated (2015) |
Source | Banco Ciudad and private consultants Official figures are substantially inferior. |
Subunit | |
1/100 | centavo |
Symbol | $ |
Coins | 5, 10, 25, 50 centavos, 1 peso, 2 pesos |
Banknotes | 2, 5, 10, 20, 50, 100 pesos |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Peso Argẹntínà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.