Èdè Árámáìkì

Èdè Árámáìkì je ara èdè Sèmítíìkì (Semitic).

Àwon tí ó ń so èdè yìí tó egbèrún lónà igba ní Ìráànù (Iran) àti Ìráàkì (Iraq) pèlú òpòlopò àwon mìíràn tí wón tún ń so ó ní Ààrin gbùngbùn ìlà-òòrùn àgbáyé (Middle tast). Láti séńtúrì kefà ni wón ti ń fi Árámáìkì àtijó (Classical Aramaic) ko nnkan sílè ní Ààrin gbingbein ìlà-oòrùn àgbáyé (Middle East). Hébéérù ni ó wá gba ipò rè gégé bí èdè tí àwon júù ń so.

Aramaic
ארמית Arāmît, ܐܪܡܝܐ Armāyâ/Ārāmāyâ
Ìpè/arɑmiθ/, /arɑmit/,
/ɑrɑmɑjɑ/, /ɔrɔmɔjɔ/
Sísọ níIran, Iraq, Israel, Lebanon, Syria, Turkey
AgbègbèThroughout the Middle East, Europe and America.
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀2,200,000
Èdè ìbátan
Afroasiatic
  • Semitic
    • West Semitic
      • Central Semitic
        • Northwest Semitic
          • Aramaic
Sístẹ́mù ìkọAramaic abjad, Syriac abjad, Hebrew abjad, Mandaic alphabet with a handful of inscriptions found in Demotic and Chinese characters.
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3variously:
arc – Imperial and Official Aramaic (700-300 BCE)
oar – Old Aramaic (before 700 BCE)
aii – Assyrian Neo-Aramaic
aij – Lishanid Noshan
amw – Western Neo-Aramaic
bhn – Bohtan Neo-Aramaic
bjf – Barzani Jewish Neo-Aramaic
cld – Chaldean Neo-Aramaic
hrt – Hértevin
huy – Hulaulá
kqd – Koy Sanjaq Surat
lhs – Mlahsô
lsd – Lishana Deni
mid – Modern Mandaic
myz – Classical Mandaic
sam – Samaritan Aramaic
syc – Syriac (classical)
syn – Senaya
tmr – Jewish Babylonian Aramaic
trg – Lishán Didán
tru – Turoyo

Èka-èdè ìwò-oòrùn èdè yìí (Western dialect) ni èdè tí Jéésù Kristì àti àwon omo èyìn rè ń so. Èka-èdè kán tí ó wá láti ara èka-èdè yìí ni wón sì ń so ní àwon abúlé kan ní ilè Síríà àti Lébánóònù.

Ní nnkan bíi séńtúrì kéje ni èdè Lárúbáwá gba ipò èdè Árámáìkì. Èka-èdè apá ìwo-oòrùn èdè yìí tí a ń pè ní Síríàkì (Syricac) ni àwon ìjo Àgùdà ará fíríàkì (Syriac Catholic) ń lò.

Álúfábéètì méjìlélógún ni èdè yìí ní. Èdè yìí sì se pàtàkì nítorí pé láti ara rè ni Hébéérù, Lárúbáwá àti àwon èdè mìíràn ti dìde.


Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

(6840) 1995 WW5KhabaAlfred NobelWúràAyéLinda IkejiConstantine ILáọ̀sÈdè LárúbáwáGustav StresemannMohamed ElBaradeiṢàngóSebastián PiñeraTsẹ́kì OlómìniraZheng HePennsylvaniaOṣù Kàrún(6065) 1987 OC21 OctoberMassachusettsÀtòjọ àwọn àjọ̀dúnMax HorkheimerFriedrich Hayek24 JuneMiguel Primo de Rivera, 2nd Marquis of EstellaỌjọ́bọ̀31 OctoberRárà21 AugustHimalayaÌbínibíEsther OnyenezideOmoni OboliOsmium23 May1 MayIlé-Ifẹ̀JerseyFránsìWashington, D.C.Kuala Lumpur31 DecemberHermann HesseSàmóà Amẹ́ríkàC++FIFA10 AprilỌdúnAfghanístànRepublican Party (United States)ISO 31-1NaijiriaDick CheneyỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ÌjíptìGoogleOṣù KínníGbolahan MudasiruKàríbẹ́ánì🡆 More