141 Lumen

141 Lumen jẹ́ ìsọ̀gbé oòrùn kékeré alápáta fífẹ̀ tí ó tó àlàjá 130 km t́ ó ń yípo ní ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tí ó wà lẹ́gbẹ́ Eunomia ẹbí àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré.

Tẹ̀gbón tàbúro Paul Henry àti Prosper Henry ló ṣàwárí rẹ̀ ní Ọjọ́ kínín Oṣù kẹtàlá Odún 1875, ṣùgbọ́n Paul ni ó gba iyì fún àwárí yìí. Wọ́n sọọ́ lórúkọ fún Lumen: Récits de l'infini, ìwé tí onímọ̀ ìwòràwọ̀ Camille Flammarion kọ.

141 Lumen
Ìkọ́kọ́wárí  and designation
Kíkọ́kọ́wárí látọwọ́ P. P. Henry
Ọjọ́ ìkọ́kọ́wárí 13 January 1875
Ìfúnlọ́rúkọ
Orúkọ mírànnone
Minor planet
category
Main belt
Àwọn ìhùwà ìgbàyípo 
Àsìkò 31 July 2016 (JD 2457600.5)
Aphelion3.23723 AU (484.283 Gm)
Perihelion 2.09253 AU (313.038 Gm)
Semi-major axis 2.66488 AU (398.660 Gm)
Eccentricity 0.21477
Àsìkò ìgbàyípo 4.35 yr (1589.0 d)
Average orbital speed 18.03 km/s
Mean anomaly 292.477°
Inclination 11.8967°
Longitude of ascending node 318.504°
Argument of perihelion 58.1076°
Àwọn ìhùwà àdánidá
Ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ 131.03±2.9 km
130 km 
131.35 ± 5.21 km 
Àkójọ (8.25 ± 5.77) × 1018 kg 
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ ~1.4 g/cm³ (estimate)
6.95 ± 4.93 g/cm3
Equatorial surface gravity~0.025 m/s² (estimate)
Equatorial escape velocity~0.06 km/s (estimate)
Rotation period 19.87 h (0.828 d) 
0.820 d (19.67 h) 
Geometric albedo0.0540±0.002
0.054 
Ìgbónásí ojúde
   Kelvin
   Celsius
minmeanmax
~173275
+2°
Spectral typeC
Absolute magnitude (H) 8.4

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Èdè TàmilOṣù KínníPáùlù ará TársùÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 20202 MayMons pubisÈdè LárúbáwáSan Jose, Kalifọ́rníàỌjọ́ Àbámẹ́taÌjímèrèAṣọ ÀdìrẹLucie ŠafářováJack Lemmon28 SeptemberÍsráẹ́lìDodaEuropeIṣẹ́ Àgbẹ̀26 MayRita WilliamsYemojaOwe YorubaTenzin Gyatso, 14th Dalai LamaÀkúrẹ́ArgonFrederica WilsonSheik Adam Abdullah Al-IloryEsther OnyenezideWikisourceMuhammadu BuhariParáDonald TrumpFriedrich HayekRárà23 May1 MayỌjọ́ ÀìkúAbacavir31 OctoberÀdírẹ́ẹ̀sì IPArkansasRobert HofstadterẸ̀bùn NobelYorùbáAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ AleiroEarthEsther OyemaIrinÀkójọ àwọn orílẹ̀-èdè Europeaue27BoriẸlẹ́ẹ̀mínFlorence Griffith-JoynerÌṣekọ́múnístìOlaitan IbrahimÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nọ́rwèy2024XMontanaFIFAỌ̀rànmíyànỌya🡆 More