Ìwé Sámúẹ́lì

Ìwé Sámúẹ́lì jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Sámúẹ́lì, ìbí rẹ̀, bí ó ti ṣe dàgbà nínú ìjọ lábẹ́ wòlíì Ọlọ́run kan Élì, tí ó sì jẹ́ láti ìgbà èwe rẹ̀ ni Ọlọ́run ti pè é.

Sámúẹ́lì ni wòlíì Ísírẹ́lì tó kàn lẹ́yìn Élì, tí ó sì ń fi iṣẹ́ tí Ọlọ́run ran gba àwọn ènìyàn rẹ̀ nípa yíyàn ọba Sọ́ọ́lù gẹ́gẹ́ bí i ọba Ísírẹ́lì àkọ́kọ́. Tí ó sì tún sọ̀rọ̀ nípa àyọrísí àwon àwọn Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí i olùborí lórí àwọn Filísínì, àti ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run láti má kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀. Abbl.

Ìwé Sámúẹ́lì
Ọba Ísírẹ́lì Lórí Ìtẹ́.

Itokasi

Tags:

Bíbélì Mímọ́

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Yunifásítì ìlú Màídúgùri3 Oṣù KejìláJay-Z5 DecemberỌjọ́bọ̀OgunÀjẹsára ọ̀fìnkìÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáColumbus, OhioÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́PCristóbal MendozaToyin Adewale-GabrielVictoria University of Manchester.cyLọ́kọ́jaUmaru Musa Yar'aduaIreland8 NovemberCaroline DanjumaIlé-Ifẹ̀PlùtòOrin-ìyìn Orílẹ̀-èdè Gúúsù ÁfríkàIslàmabadDaniel O. FagunwaÌṣeọ̀rọ̀àwùjọRemi AdedejiPhillip Allen SharpJohn H. JohnsonTèmítọ́pẹ́ ṢólàjàTobi BakreGlenn T. SeaborgRMọfọ́lọ́jì èdè YorùbáSátúrnùÈdèe YorùbáÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ PólàndìGeorge WeahGírámà YorùbáAndhra PradeshWiki CommonsÌnàkíOwe YorubaHypertext Transfer ProtocolMarie-Joseph Motier, Marquis de LafayetteAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá IjebuISBNÈdè JapaníJohn Hasbrouck Van VleckBill RussellAbẹ́òkútaMercury (planet)Wikipẹ́díà l'édè YorùbáPólándìÀkójọ àwọn àmìọ̀rọ̀ ìpè tẹlifónù orílẹ̀-èdèIdris KutigiÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ SòmálíàMichael Bamidele OtikoTẹlifísànÌpínlẹ̀ ÒgùnNelson MandelaAtiku AbubakarGùyánà FránsìAdo EkitiÀjọ tí ó ń mójú tó ońjẹ àti oògùn ti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkàBennet OmaluGalileo GalileiNellymoser Asao Codec🡆 More