Ìwé Sámúẹ́lì

Ìwé Sámúẹ́lì jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Sámúẹ́lì, ìbí rẹ̀, bí ó ti ṣe dàgbà nínú ìjọ lábẹ́ wòlíì Ọlọ́run kan Élì, tí ó sì jẹ́ láti ìgbà èwe rẹ̀ ni Ọlọ́run ti pè é.

Sámúẹ́lì ni wòlíì Ísírẹ́lì tó kàn lẹ́yìn Élì, tí ó sì ń fi iṣẹ́ tí Ọlọ́run ran gba àwọn ènìyàn rẹ̀ nípa yíyàn ọba Sọ́ọ́lù gẹ́gẹ́ bí i ọba Ísírẹ́lì àkọ́kọ́. Tí ó sì tún sọ̀rọ̀ nípa àyọrísí àwon àwọn Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí i olùborí lórí àwọn Filísínì, àti ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run láti má kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀. Abbl.

Ìwé Sámúẹ́lì
Ọba Ísírẹ́lì Lórí Ìtẹ́.

Itokasi

Tags:

Bíbélì Mímọ́

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

UNICEFKelly RowlandẸ̀bùn Àláfíà NobelLúksẹ́mbọ̀rgOwe YorubaRoger FedererRichard FeynmanÈdè GermanyPolinésíà FránsìNàìjíríàOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìJamaicaYinusa Ogundipe Arapasowu IPresident of the United StatesLangston HughesÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ MàkáùÈdè JavaAmẹ́ríkàMayotteRichard NixonLùsíà Mímọ́ApricotÀàrẹÒjéṢàngóIPhoneUsherPólándìÌtàn ilẹ̀ Siẹrra LéònèAlbert Einstein2001Abdelmadjid TebbouneMichael CaineOnchocerciasisFránsìPatrick LeahyNorth AmericaJames A. GarfieldÀwọn Erékùṣù KánárìÀìsàn ẹ̀jẹ̀ ríruPópù Sylvester 1kFriedrich EngelsSubrahmanyan ChandrasekharLech WałęsaMilton FriedmanÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìDenis IstominJohn Maynard KeynesBernice Carr VukovichẸranko afọmúbọ́mọBaltimoreÀtòjọ àwọn oúnjẹ Ilẹ̀ Adúláwọ̀JacksonvilleẸ̀bùn PulitzerZafarullah Khan JamaliMinskXHavanaAkanlo-edeAntárktìkàMáàdámidófòFilipínìWallis and FutunaPópù Gregory 13kRománíàRobert B. LaughlinHonoluluBeijingLeonid BrezhnevPornhubKikan Jesu mo igi agbelebuNASA🡆 More