Ìjalèlókun jẹ́ ìwa olèjíjà tàbí ìwà ọ̀daràn ní okun.
Àwọn tí ó ń lọ́wọ́sí ìwà Ìjalèlókun ni wọ́n ń pè ní àwọn ajalèlókun. Àkosílẹ̀ àpẹẹrẹ ìjalèlókun tí ó pẹ́jù ṣẹlẹ̀ ní bíi Orundún mẹ́rìnlá sẹ́yìn, nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ ajalè lórí òkun dojú kọ ọkọ̀ ojú omi ti Aegean àti Mediterranean tí kò digun. Àwọn ònà tóóró tí ó ń jẹ́ kí wọn mọ ònà ibi tí ọkọ̀ ojú omi gbà ń fa ààyè fún ìjalèlókun, tí ó tún ń fa ààfàní fún idigun ja ọkọ̀ ojú omi àti oníṣowò ojú omi.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ìjalèlókun, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.