Àsìá ilẹ̀ Kìrìbátì jẹ́ àsìá oŕilẹ̀-èdè.
Ó nì àwọ́ pupa nì apá òkè pẹ̀lú eye góólù tí, ó fò lórí ìtànsán òòrùn pèlú àwọ̀ bọ́ọ̀lù ní apá ìsàlẹ̀ àti ìlà funfun tẹ́ẹ́rẹ́ mẹ̀ta. Àsìá náà jáde ní ọjọ́ kejìlá osù keje, ọdún 1979. Àwọ̀ funfun àti búúlù rẹ̀ túmọ̀ sí àwọn adágún odò ńlá tí o ́yíí óriĺẹ̀ - èdè náà kà. Eye tí ó ń fò lóríi ìtànsán òòrùn ná̀à túmọ̀ sí okun àti agbára àwọn adágún odò náà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àsìá ilẹ̀ Kìrìbátì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.