Wally Adéyẹmọ

Adéwálé Wally Adéyẹmọ (wọ́n bí i lọ́dún 1981) jẹ́ Ààrẹ àkọ́kọ́ fún àjọ-aṣàánú, Obama Foundation tí Ààrẹ àná orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Barack Obama dá sílẹ̀.

During the Obama Administration, Adéyẹmọ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí igbákejì olúdámọ̀ràn lórí ètò àbò fún àjọ ètò ọ̀rọ̀-ajé àgbáyé,International Economics lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 2015 sí 2016, bẹ́ẹ̀ náà òun ni igbá-kejì ọ̀gá àgbà ti National Economic Council.

Wally Adéyẹmọ
Wally Adéyẹmọ
Official portrait, 2021
15th United States Deputy Secretary of the Treasury
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
March 26, 2021
ÀàrẹJoe Biden
SecretaryJanet Yellen
AsíwájúJustin Muzinich
President of the Obama Foundation
In office
August 1, 2019 – March 25, 2021
AsíwájúPosition established
Arọ́pòValerie Jarrett
United States Deputy National Security Advisor for International Economics
In office
2015–2016
ÀàrẹBarack Obama
AsíwájúCaroline Atkinson
Arọ́pòDaleep Singh (2021)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Adewale O. Adeyemo

Oṣù Kàrún 20, 1981 (1981-05-20) (ọmọ ọdún 42)
Ibadan, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèAmerican
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
Education
  • UC Berkeley (BA)
  • Yale University (JD)

Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀

Adéyẹmọ dàgbà sí Los Angeles, California. Ó kàwé gboyè Bachelor of Arts láti University of California, Berkeley àti Juris Doctor láti Yale Law School.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Barack Obama

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

HimalayaAlbert Abraham MichelsonÁntígúà àti BàrbúdàSvalbardKareem Abdul-JabbarÀtòjọ àwọn olórí ìjọba àti orílẹ̀-èdè lọ́wọ́lọ́wọ́22 AugustIrinRihannaProgressive Graphics FileGNọ́mbà átọ̀mùẸgbẹ́ Dẹmọkrátíkì (USA)Ìṣọ̀kan ÁfríkàGran CanariaBismuthEyvind JohnsonJohn Quincy AdamsÈdè GermanyKòréà GúúsùÈdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàZheng HeÀsìá ilẹ̀ UkréìnGeorgiaAarhusÌlú KuwaitiPsusennes 1kÒjòFaustin-Archange TouadéraPhiladelphiaSophia LorenPepsiOlóṣèlúIvan DodigÌgbà DẹfoníàKarim MassimovÀwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyànLebanonÀtòjọ àwọn àjọ̀dúnÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìIretiola DoyleIndo-European languagesWallis àti FutunaSam Amuka-PemuLahoreLimp BizkitOṣù Kínní 1622 SeptemberNọ́mbàAyoka Olufunmilayo AdebamboAzerbaijanÀsìkòTitaniomu21 MarchNATOJMark ZuckerbergAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéIrakÀtòjọ àwọn akọ̀ròyìn ilẹ̀ NàìjíríàOlúìlúDelhiAugusto B. LeguíaIoannis KolettisDale T. MortensenÒjéÀsìá ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàKrypton12 May🡆 More