Us Army School Of Infantry

United States Army Infantry School tí ó wà ní ìlú Fort Benning ni Ìpínlẹ̀ Georgia jẹ́ ilé-ìwé tí ó wà fún kíkọ́ àwọn ológun ilẹ̀ Amerika, United States armed forces.

Us Army School Of Infantry
Àmì Ilé ìwé United States Army Infantry

Ètò ilé-ìwé

llé-ìwé náà pín sí ẹ̀ka oríṣiríṣi, bíi:

  • Us Army School Of Infantry  Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndílọ́gbọ̀n
    • Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndíláàádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kẹta, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kẹta, ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnléláàádọ́ta
  • Us Army School Of Infantry  Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejìdínláàádọ́ẁá
    • Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlógún
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun eleekokandinlogun
    • Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun àádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnléláàádóta
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlọ́gọ́ta

Fún àwọn èèyàn to ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé, ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá àti ẹlẹ́ẹ̀kejìdínláàádọ́ẁá máa ń gba ẹ̀kọ́ fún ọ̀sẹ̀ méjìlélógún. Àfojúsùn àwọn ọ̀wọ́ yìí ni láti ṣe ìyípadà fún àwọn ará-ìlú láti di ọmọ-ológun tó já fáfá, tó kúnjú òṣùwọ̀n, tó ní ìwà ọmọ-ológun, tó dúró ire, tó níwà gidi, tó sì ń ṣiṣẹ́ dédé kí wón ba lè nì ìtẹ́wọ́gbà sínú ẹgbẹ́ náà.

  • Us Army School Of Infantry  Àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínláàádọ́ẁá
    • Ọ̀wọ́ kejì, ọmọ-ogun ìkọkànlá
    • Ọ̀wọ́ kẹta, ọmọ-ogun ìkọkànlá
    • Ọ̀wọ́ kẹta, ọmọ-ogun ìkọkànlélọ́gọ́rin
    • Ìwé àwọn akọgun
    • Akádẹmì àwọn ológun aláìnígbìmọ̀ ti Henry Caro
      • Ẹ̀kọ́ àwọn adarí àgbà ti Maneuver tí ó fìgbà kan jẹ́ ẹ̀kọ́ àwọn ológun aláìnígbìmọ̀
      • Àfikún ẹ̀kọ́ àwọn àgbà adarí tí ó fìgbà kan jẹ́ ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún àwọn ológun aláìnígbìmọ̀
      • Ẹ̀kọ́ àwọn adarí ogun tí ó fìgbà kan jẹ́ ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún ìdàgbàsókè àwọn adarí
  • Us Army School Of Infantry  Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ológun ti òfurufú
    • Us Army School Of Infantry  Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun eleekerin
      • Ile-iwe awon ọmọ-ogun (ti Benning)
    • Us Army School Of Infantry  Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀karùn-ún
      • Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun (ti Mountain)
    • Us Army School Of Infantry  Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹfà
      • Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun (ti inú-irà)
    • Us Army School Of Infantry  Ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ogun kìíní, Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejelélẹgbẹ̀fà
      • Ilé-ìwé àwọn ajagun ti orí òfurufú
      • Ilé-ìwé àwọn jumpmaster
      • Àwon ọmọ Silver-wings
  • Adarí ajagun àpapọ̀

Àwọn ọmọ-ogun tó ti parí ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún àwọn adarí máa ń lọ sí ọ̀wọ́ kejì láti gba Ìdánilẹ́kọ̀ọ́. Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí wà fún ìgbaniníyànjú àti ẹ̀kó tó yè koro, kí wọ́n ba lè nímọ̀ nípa ìbọn lílò àti ìmọ̀ọ́ṣe nìgbogbo ọ̀nà.

Ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ogun yìí tún máa gbé Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kalẹ̀ fún ìmọ̀ níní nínu ogun orí òfurufú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Adarí ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun

Adarì ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun máa ń jẹ́ olórí àti olùdarí ilé-ìwé yìí.

No. Àwòrán Orúkọ Ìbẹ̀rẹ̀ Òpin
1 Colonel Henry E. Eames 5 October 1918 22 April 1919
2 Major General Charles S. Farnsworth 22 April 1919 31 July 1920
3 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Walter H. Gordon 1 August 1920 8 November 1923
4 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Briant H. Wells 9 November 1923 8 March 1926
5 Brigadier General Edgar T. Collins 9 March 1926 1 May 1929
6 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Campbell King 2 May 1929 31 May 1933
7 Brigadier General George H. Estes 1 June 1933 30 September 1936
8 Brigadier General Asa L. Singleton 1 October 1936 31 August 1940
9 Us Army School Of Infantry  Major General Courtney Hodges 1 September 1940 3 March 1941
10 Us Army School Of Infantry  Major General Omar N. Bradley 4 March 1941 10 February 1942
11 Major General Leven C. Allen 11 February 1942 18 September 1943
12 Us Army School Of Infantry  Major General Charles H. Bonesteel Jr. 19 September 1943 27 June 1944
13 Us Army School Of Infantry  Major General Fred L. Walker 28 June 1944 11 July 1945
14 Us Army School Of Infantry  Major General John W. O'Daniel 12 July 1945 1 July 1948
Us Army School Of Infantry  Major General John W. Foss 1983 1985
Us Army School Of Infantry  Major General Kenneth C. Leuer 1987 1989
47 Us Army School Of Infantry  Major General Benjamin Freakley 2003 2005
48 Us Army School Of Infantry  Major General Walter Wojdakowski 2005 2008
49 Us Army School Of Infantry  Major General Michael Barbero 2008 2009
50 Us Army School Of Infantry  Major General MIchael Ferriter 2009 2009
51 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Bryan Owens 2009 2011
52 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Walter E. Piatt 2011 2012
53 Us Army School Of Infantry  Brigadier General David B. Haight 2012 2013
54 Us Army School Of Infantry  Colonel Robert E. Choppa 2013 2014
55 Us Army School Of Infantry  Brigadier General James E. Rainey 2014 2015
56 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Peter Jones 2015 2017
57 Us Army School Of Infantry  Brigadier General Christopher T. Donahue 2017 2018
58 Us Army School Of Infantry  Colonel Townley R. Hedrick 2018 2018
59 Us Army School Of Infantry  Major General David M. Hodne 2018 2021
60 Us Army School Of Infantry  Brigadier General, Larry Q. Burris Jr. 2021 Current

Àwọn ìtọkasí

Ìjápọ̀ mìíràn

Tags:

Us Army School Of Infantry Ètò ilé-ìwéUs Army School Of Infantry Adarí ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogunUs Army School Of Infantry Àwọn ìtọkasíUs Army School Of Infantry Ìjápọ̀ mìírànUs Army School Of InfantryUnited States armed forcesÌpínlẹ̀ Georgia

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Gírámà YorùbáEugenio MontaleSune Bergström22 June8 MayLucie ŠafářováJames D. WatsonPorto NovoAdenike OlawuyiOṣù KẹfàOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàAndré Frédéric CournandInstagramAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ IkoleIgbesi aye mi ninu igbo ti Awọn ẹmi (aramada)George Walker BushTurkmẹ́nìstánÌnàkíGúúsù SudanÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2004Vladimir Lenin17 OctoberÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìEukaryoteGarba DubaQChinedu IkediezeRáràOffice Open XMLẸkún ÌyàwóÒmìniraH. H. AsquithDysprosiumTógòÌbálòpọ̀Ìṣekọ́múnístìMadridPópù Agapetus 2kIodineZambiaWikimedia24 JuneRamesses VIIFlorence Griffith-JoynerWalter Rudolf HessFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìYorùbáTsẹ́kì OlómìniraISO 639-2TegucigalpaẸlẹ́ẹ̀mínVictoria UmunnaGbolahan MudasiruGrover ClevelandAbdullahi Ibrahim (ológun)Abubakar Tafawa BalewaAdetokunbo Ademola2010San Màrínòaue2721 AugustÀṣà YorùbáBD MimọMóldófàStephen HarperÌpínlẹ̀ Ògùn(6065) 1987 OCÌran YorùbáLogicNọ́mbà átọ̀mùBenjamin Mkapa🡆 More