Tsung-Dao Lee tàbí T.D.
Lee, (bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún Oṣù kọkànlá Ọdún 1926) jẹ́ aṣisẹ́olóhungidi ọmọ orílẹ̀ èdè China ará Amẹ́ríkà tó gba Ẹ̀bùn Nobel nínú ìmọ̀ Physics ní ọdún 1957.
Tsung-Dao (T.D.) Lee | |
---|---|
Tsung-Dao Lee | |
Ìbí | 24 Oṣù Kọkànlá 1926 Shanghai, China |
Ará ìlẹ̀ | United States (1962-present) |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of California, Berkeley Columbia University |
Ibi ẹ̀kọ́ | Zhejiang University National Southwestern Associated University University of Chicago |
Doctoral advisor | Enrico Fermi |
Ó gbajúmọ̀ fún | Parity violation Lee Model Non-topological solitons Particle Physics Relativistic Heavy Ion (RHIC) Physics |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1957) Albert Einstein Award (1957) |
Signature |
Ẹ̀yẹ:
Ọmọ ẹgbẹ́:
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Tsung-Dao Lee, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.