Miriam Màkébà tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù Kẹta ọdún 1932 tí ó sìn di olóògbé ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 2008 (4 March 1932 - 10 November 2008) jẹ́ akọrin àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ ènìyàn ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Gúúsù Afíríkà.
Ó gba Ẹ̀bùn Grammy. Orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ tó gbajúmọ̀ ni Mama Afrika.
Miriam Makeba | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Zenzile Miriam Makeba |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Mama Afrika |
Occupation(s) | Singer |
Years active | 1954-2008 |
Labels | Manteca, RCA, Mercury Records, Kapp Records, Collectables, Suave Music, Warner Bros., PolyGram, Drg, Stern's Africa, Kaz, Sonodisc |
Website | Official Website |
Zenzile Miriam Makeba jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Johannesburg, Olú ìlú Gúúsù Áfíríkà. Wọ́n bí I lọ́dún ni 1932. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Swazi sangoma. Bàbá rẹ̀ kú nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́fà, orúkọ rẹ̀ Xhosa. Nígbà èwe rẹ̀, oy korin ní Kilmerton Training Institute ní Pretoria, níbi tó ti kẹ́kọ̀ọ́ fún ọdún mẹ́jọ.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Miriam Makeba, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.