Michael D. Higgins

Michael Daniel Higgins (Irish: Mícheál D.

Ó hUiginn; bibi 18 April 1941) ni aare adiboyan ile Irelandi, yio si di Aare ile Irelandi kesan, leyin igb to bori idiboyan aare Irelandi 2011 to waye ni 27 October 2011. Higgins je oloselu, akoewi, aseoroalawujo, akowe ati akede ara Irelandi. Higgins je Aare Labour Party of Ireland titi di igba to feyinti kuro nibi egbe oloselu leyin idiboyan aare. Teletele o je Teachta Dála (TD) fun agbegbe Galway West, be sini ohun lo je Alakoso fun Iseona, Asa ati Gaeltacht lati 1993 de 1997.

Michael D. Higgins
Michael D. Higgins
President-elect of Ireland
Taking office
11 November 2011
SucceedingMary McAleese
Minister for Arts, Culture and the Gaeltacht
In office
15 December 1994 – 26 June 1997
AsíwájúBertie Ahern
Arọ́pòSíle de Valera
In office
12 January 1993 – 17 November 1994
AsíwájúJohn Wilson
Arọ́pòBertie Ahern
Teachta Dála
In office
17 February 1987 – 25 February 2011
AsíwájúFintan Coogan
Arọ́pòDerek Nolan
In office
11 June 1981 – 24 November 1982
AsíwájúSeat established
Arọ́pòFintan Coogan
ConstituencyGalway West
Senator
In office
23 February 1983 – 3 April 1987
ConstituencyNational University of Ireland
In office
1 June 1973 – 26 May 1977
ConstituencyTaoiseach's nominee
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹrin 1941 (1941-04-18) (ọmọ ọdún 83)
Limerick, Ireland
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent (2011–present)
Other political
affiliations
Labour Party (Before 2011)
(Àwọn) olólùfẹ́Sabina Coyne
Àwọn ọmọ4
Alma materUniversity College, Galway
Indiana University, Bloomington
University of Manchester




Itokasi

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Christian BaleStockholmỌdúnMontanaVincent van Gogh12 DecemberMarseilleMao Zedong30 MayNaijiriaLisbonÀwọn èdè Índíà-EuropeRichard WagnerWikipediaOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàYorùbáÈdè iṣẹ́ọbaBD MimọAjah, LagosÌpínlẹ̀ ÍmòÒṣèlú633 ZelimaỌjọ́ ÀìkúC++ISO 4217IléÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáDodaTuedon MorganGaza StripAssam21 JuneAdenike OlawuyiAndré Frédéric CournandAbubakar Tafawa BalewaÀdírẹ́ẹ̀sì IPSÀpàlà12 AprilÌgbà SílúríàAssouma UwizeyeAbdullahi Ibrahim (ológun)Peter O'Toole(6840) 1995 WW5Írẹ́lándì ApáàríwáÌwéTógòGírámà YorùbáWikiOnímọ̀ ìsirò3 MayLèsóthòEwìOlaitan IbrahimÌyáDick Cheney10 FebruaryPotsdamAalo Ìjàpá àti elédèWúràJohn Sparrow David Thompson23 December234 BarbaraGúúsù-Ìlàòrùn Ásíà🡆 More