Kehinde Smith

Kehinde Smith jẹ́ Òǹtajà tó ní àṣeyọrí lórí okòwò rẹ̀, bákan náà ni ó jé olùdarí ati Olùdásílẹ̀ beauty Brand tí wọn ń pè ní MY EXTENSIONZ: tí ó dá sílẹ̀ ní orílé-èdè United Atare láti bí ọdún mẹ́fà sẹyìn, àti ní orílé èdè Nàìjíríà.

Kehinde Smith tẹ̀síwájú láti tún bẹrẹ fẹ́ My Extension lójú sí ní orílé èdè Nàìjíríà nípa fífi Irun àti ṣíṣe Èẹkánná àti kí á ló Laser láti fí jékí ẹyin mọ (laser teeth whitening centre). Ọ jé gbajúmò níbi kí bá tá Virgin hair àti 3D Nini Lashes àti àwọn ohun oge ṣíṣe miiran; My Extension tí wá lára àwọn tí ó tayọ níbi ká ṣe Irun àti ta àwọn ohun tó jẹ mọ oge ṣíṣe. Lára ṣíṣe ìwádìí lórí Irun oge ṣíṣe, ọ wá lára àwọn tí wón Yan fún Future Awards Africa for Beauty ni ọdún 2016. Ní ọdún 2017, Kehinde mú ohun tí ó fẹràn gege bí iṣẹ beauty and lifestyle Influencer. Ní bí kí a mú iṣẹ ni òkùnkùndùn, àti ìṣe àṣẹkára ni ọ jẹ́ kí ó ní àwọn tí 70,000 followers lórí ẹrọ Instagram kí oṣù meje ó tó pé orúkọ rẹ̀ sí ń jẹ́ "Your Melanin Godmother". Páge rẹ lórí Instagram jẹ́ kí ó ní àpèjúwe tí ó yanranti tí ó jé kí àwọn àwòrán rẹ gúnrégé, èyí tí ó ń gbe àwọ dúdú ga tí ó sí jẹ́ òun ìwúrí fún àwọn obìnrin yòókù láti ṣé òun tí ó ń ṣe. Bákanáà ní ọ tí gbà àwọn àmì ìdámò àti ìfọwọ́sí láti àwọn ilé iṣé òkèrè bí Revolve, Oh Poly, Sinmi àti bẹẹ bẹẹ lọ. Ó Pinnj lati fi àwọn ipa re gẹgẹ bí Brand Ambassador tí Revolve clothings láti fi tún bọ́ ṣe alagbawi fun onírúurú ilé iṣé yálà lókè òkun tàbí ní ilẹ Nàìjíríà.

Itokasi

Tags:

Nàìjíríà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Iowa2 August1016 AnitraOlaitan IbrahimFáwẹ̀lì YorùbáOṣù KẹtaMọ́skòÌjímèrèMóldófàEsther OyemaMassachusettsBangladẹ́shìLizzy jayOṣù KẹfàPópù Victor 3kJohn Carew EcclesMajid Michel26 SeptemberEugenio MontaleDVOregonÌpínlẹ̀ ÒgùnFránsìGúúsù SudanOṣù Kẹ̀sánLaurent FabiusCopenhagenAndré Frédéric CournandAdunni AdeÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÍndíà22 JuneISO 31-1Orílẹ̀ èdè AmericaKàlẹ́ndà GregoryDArizonaÌṣeọ̀rọ̀àwùjọCheryl Chase (activist)Ibadan Peoples Party (IPP)PotsdamDaisy DucatiIodineKárbọ̀nùPópù Jòhánù Páúlù ÈkejìVP3Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé FIFA 2006Richard WagnerỌjọ́ 25 Oṣù KẹrinGrover Cleveland30 AprilGodwin ObasekiAlaska1 AugustÒkun ÁrktìkìÀlọ́(5813) 1988 VLÀdánidáCharles J. Pedersen22 OctoberR. Kelly950 Ahrensa🡆 More