Joyce Hilda Banda née Mtila (ojoibi 12 April 1950) je oloselu are Malawi to ti unse Aare ile Malawi lati ojo 7 Osu Kerin 2012.
Banda je oluko ati alakitiyan eto awon obinrin. O wa nipo bi Alakoso Aro Okere lati 2006 de 2009 ati Igbakeji Aare ile Malawi lati May 2009 de April 2012. Banda took office as President following the sudden death of President Bingu wa Mutharika. Ohun ni aare ikerin ile Malawi ati aare akoko to je obinrin.
Joyce Banda | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Màláwì | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 7 April 2012 | |
Vice President | Khumbo Kachali |
Asíwájú | Bingu wa Mutharika |
Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Màláwì | |
In office 29 May 2009 – 7 April 2012 | |
Ààrẹ | Bingu wa Mutharika |
Asíwájú | Cassim Chilumpha |
Arọ́pò | Khumbo Kachali |
Alakoso Oro Okere | |
In office 1 June 2006 – 29 May 2009 | |
Ààrẹ | Bingu wa Mutharika |
Asíwájú | George Chaponda |
Arọ́pò | Etta Banda |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹrin 1950 Malemia, Nyasaland (now Malawi) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United Democratic Front (Before 2004) Democratic Progressive Party (2004–2010) People's Party (2011–present) |
{{{blank1}}} | Roy Kachale (de 1981) Richard Banda |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Joyce Banda, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.