Richard Claxton Gregory (Ọjọ́ kejìlá Oṣù kẹwá ọdún 1932 – Ọjọ́ ọ̀kàndínlógún Oṣù kẹjọ ọdún 2017) jẹ́ aláwàdà, alákitiyan eto araalu, alárìíwísí, olùkòwé, oníṣòwò, àti òṣèré ará Áfíríkà bi Amẹ́ríkà.
Dick Gregory | |
---|---|
Gregory in 2015 | |
Orúkọ àbísọ | Richard Claxton Gregory |
Ìbí | St. Louis, Missouri, U.S. | Oṣù Kẹ̀wá 12, 1932
Aláìsí | August 19, 2017 Washington, D.C., U.S. | (ọmọ ọdún 84)
Medium | Civil rights activist, stand-up comedy, film, books, critic |
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdè | American |
Years active | 1954–2017 |
Genres | Civil Rights |
Subject(s) | American civil rights, politics, culture, African-American culture, racism, race relations, vegetarianism, healthy diet |
Spouse | Lillian Smith (m. 1959) |
Notable works and roles | In Living Black and White Nigger: An Autobiography by Dick Gregory Write Me In! "Fire, The Dick Gregory Story, by Shelia P. Moses |
Ibiìtakùn | www.dickgregory.com |
[1][Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Dick Gregory, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.