Deji Akinwande jẹ́ ọmọ orílẹ̀ Naijiria tó sì tún tan mọ́ ilẹ̀ America.
Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Electrical and Computer Engineering tó sì tún ní àsopọ̀ mọ́ Materials Science ní University of Texas at Austin. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Presidential Early Career Award for Scientists and Engineers ní ọdún 2016 láti ọwọ́ Barack Obama. Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ American Physical Society, African Academy of Sciences, Materials Research Society (MRS), àti IEEE.
Deji Akinwande | |
---|---|
Akinwande shakes hands with President Barack Obama, while receiving the PECASE in 2016 | |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Texas at Austin |
Ibi ẹ̀kọ́ | Stanford University Case Western Reserve University |
Doctoral advisor | H.-S. Philip Wong |
Ó gbajúmọ̀ fún | 2D materials, flexible and wearable nanoelectronics, nanotechnology, STEM education |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | PECASE, given in 2016 Fellow of American Physical Society Fellow of IEEE. Fellow of the MRS. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Deji Akinwande, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.