Peter Abelard A bí i ní 1079.
Ó kú ní 1142. Ó jé òkan lára àwon tí ó sèdá ohun tí a n pè ní scholastic theology. Olùkó ni ní Paris. Òpò akékòó ni ó máa n wá sódò rè. Òpin ìfé láàrin òun àti Heliose kò dára
Pierre Abélard | |
---|---|
"Abaelardus and Heloïse surprised by Master Fulbert", by Romanticist painter Jean Vignaud (1819) | |
Orúkọ | Pierre Abélard |
Ìbí | 1079 |
Aláìsí | 21 April 1142 |
Ìgbà | Medieval Philosophy |
Agbègbè | Western Philosophers |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Scholasticism |
Ìjẹlógún gangan | Metaphysics, Logic, Philosophy of language, Theology |
Àròwá pàtàkì | Conceptualism, Scholasticism |
Ipa látọ̀dọ̀ Aristotle, Porphyry, Boethius | |
Ìpa lórí John of Salisbury |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Peter Abelard, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.