Apaadi

Apaadi jẹ́ fíìmù Yorùbá ti ilẹ̀ ọdún 2009.

Ó jẹ́ fíìmù adá-lórí-ìtàn-gidi, èyí tí Funke Akindele máa kọ́kọ́ ṣe, òun náà sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akópa eré náà. Africa Movie Academy Awards yan fíìmù náà ní ọdún 2009, fún fíìmù tó dára jù lọ ní èdè Afrika àti ìṣeyege nínú asọ eré. Wọ́n sì yan Femi Adebayo fún òṣèrékùnrin tó dára jù, fún ìkópa rẹ̀ nínú eré náà.

Apaadi
AdaríAbiodun Olanrewaju
Olùgbékalẹ̀Funke Akindele
Àwọn òṣèréFunke Akindele
Femi Adebayo
Yinka Quadri
Taiwo Hassan
Adebayo Salami
Ronke Odusanya
Peju Ogunmola
Opeyemi Aiyeola
Sola Kosoko
Moji Olaiya
Lola Margret
Peter Fatomilola
Ilé-iṣẹ́ fíìmùScene One Productions
OlùpínOlasco Films Nig. Ltd.
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba

Àwọn àmì-ẹ̀ye àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ

Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Olùgbà Èsì Ìtọ́ka
2009 Africa Movie Academy Awards Best Film in African Language Apaadi Wọ́n pèé
Achievement in Costume Apaadi Wọ́n pèé
Best Supporting Actor Femi Adebayo Wọ́n pèé

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Femi AdebayoFunke Akindele

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

26 DecemberHypertext Transfer ProtocolỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀James Clerk MaxwellInternet Relay ChatPlùtòSikiru Ayinde BarristerRoger Wolcott SperryVArabLagos State Fire ServiceCasimir BetelWindows Media AudioDWikipẹ́díà l'édè YorùbáÀkójọ àwọn èdè iṣẹ́ọbaYuan T. LeeSouth African randEl SalfadorBonaireGeneral Exchange FormatÈdè Gẹ̀ẹ́sìÀjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Sàó Tòmẹ̀ àti PrincipeAllan McLeod CormackFẹ́mi GbàjàbíàmílàEric Allin CornellÌnáwóÀkójọ àwọn àmìọ̀rọ̀ ìpè tẹlifónù orílẹ̀-èdèÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Pólàndì1341 EdméeSpratly IslandsIslàmabadNaijiriaYÌdíje Wimbledon 1999 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanXJohn HowardUNESCOMáàdámidófòIfáÈdè Yorùbá.cvIrakÀkúrẹ́13 May20 SeptemberTYunifásítì ìlú MàídúgùriWikimediaÀsìá ilẹ̀ Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kanRichard J. RobertsPashtoZainab BalogunKinshasa27 SeptemberTomás Estrada PalmaAjodun odun BadagryÀjẹsára ọ̀fìnkìÌlàòrùn TimorAndhra PradeshIngrid BergmanAbdul-Azeez Olajide AdediranOjúewé Àkọ́kọ́Èdè FaranséKọ̀mpútàRealMedia7998 GoncziAdo Ekiti🡆 More