Àwọn èsì àwárí fún
Ojúewé tó ún jẹ́ "Ọ̀rúnmìlà" wà lórí Wikipedia Ẹ tún wo àwọn èsì ìwárí míràn tó jáde.
Ọ̀rúnmìlà tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí i (Ọ̀rúnmìlà, Orúnla, Orúla tàbí Ọ̀rún ló mọ ẹni tí yóó là, ní ilẹ̀ Yorùbá ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Latin America) jẹ́... |
(oníyẹ̀míwò) máa ń lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ láti lè sọ̀rọ̀ pọ̀ pẹ̀lú òòṣà ọgbọ́n/ìmọ̀ (Ọ̀rúnmìlà) nínú ìsẹ̀ṣe Yorùbá ẹni tí ó lè ṣe àfihàn okùnfà àti ojútùú sí ìsòri àdáni... |
ìgbà tí ìwà fi ilé Ọ̀rúnmìlà sílẹ̀. Ẹ̀mí náà jẹ ọkan lára obìnrin ọ̀rúnmìlà. Ifá fi ẹ̀mí hàn gẹ́gẹ́ bi ọ̀pọ́múléró. Ìdí nìyí tí Ọ̀rúnmìlà fí gbé ẹ̀mí ni ìyàwó... |
ifá ńṣe. Ìtàn sọ fún wa wípé ọmọ mẹ́jọ ni ọ̀rúnmìlà bí nígbà tí ó wà láyé, nígbà tí ó di ọjọ́ kan ti ọ̀rúnmìlà ńṣe ọdún ni ọ̀kan nínú àwọn ọmọ yìí tíí ṣe... |
wọ́n dífá fún. Lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn Babaláwo ló ma ń báni ṣètùtù, àyàfi tí Ọ̀rúnmìlà bá fòté le wípé Oníṣègùn kannpàtó ló gbọ́dọ̀ rúbọ náà. Iṣẹ́ àwọn oníṣègùn... |
adáríhurun. Bákan náà ló tún jẹ́ ìmọ̀ ọ̀nà ìwádìí tí Elédùà yọ̀nda fú Ọ̀rúnmìlà baba Àgbọnìrègún láti fi ṣọmọ aráyé lóore. Àwọn odù Idá wọ̀nyí dà bí ojúpọ̀nà... |
ìgbà kan gbogbo òrìṣa fẹ̀sùn kan ọ̀rúnmìlà níwájú olódùmarè lẹ́yin tí tọ̀tún tòsì wọ́n rojọ́ olódùmarè dá ọ̀rúnmìlà láre, odù ifá kan jẹri sí eléyìí,... |
Yorùbá máa ń sọ wí pé iṣẹ́ ọlọ́run tóbi tàbí àwámárídì ni iṣẹ́ olódùmarè. ọ̀rúnmìlà lọ́ fẹ̀yìntì, ó wo títítítí ó ní ẹ̀yin èrò òkun, ero ọ̀sà ǹ jẹ́ ẹ̀yin... |
Philosophy); (1997) Philosophy and Oral Tradition; (2014) Socrates and Ọ̀rúnmìlà: Two Patron Saints of Classical Philosophy; (2014) African Myths and Legends... |
Ọlọ́run - Olù kápá ọ̀run. Ọlọ́fin - Olù sààmì láàrín ọ̀run àti Ayé Ọ̀rúnmìlà - Ó jẹ́ òrìṣà ọlọ́gbọ́n, ìpín, àti arínú róde. Orí - Ó jẹ́ òrìṣà tí ó... |
rẹ̀ Ológbìín tọ Ọ̀rúnmìlà lọ. Nígbà tí ó débà tí ó débẹ̀, ó ńi “emi ló dé tí ìyàwó òun fi rọ́mọ lẹ́hìn adìẹ tó bú púrú sẹ́kún?” Ọ̀rúnmìlà sì sọ fún un pé... |
tí kò sí nínú àwọn ọdún wọn. Nípa èyí, kòsí ìyàtọ̀ láàrin Odùduwà àti Ọ̀rúnmìlà; àwọn wọnyí ní ipá pàtàkì tí wọ́n ní ní orílé Adúláwọ̀ ṣùgbọ́n tí ipá... |
Atótó ó ó ó; Atótó Arére, ẹ yáa dákẹ́ Ifá fẹ́ fọhùn; Ẹ ẹ dákẹ́. Ègbè: Ọ̀rúnmìlà o ò; Aatótó ó ó ó; Atótó ó ó Aaarére e e, Ẹ yá a dákẹ́, Ifá fẹ́ fọhùn... |