Òkun Índíà: Òkun

Òkun Índíà ni Òkun Eleketa ti o tobi Ju lo ni Àgbáyé lehin Òkun Atlántíkì, ati okun Pasifiki.

Ni iha Iwo Orun si okun naa, ni Orile erekusu Afrika,ni iha Ila Orun si okun naa si ni apa Ila orun-Guusu orile erekusu Asia.Si ariwa okun naa ni apa guusu Asia. Orile ede ti o tobi ju lo, Ninu awon orile ede ti o wa ni iha naa ni orile ede India, nibi ti okun naa ti mu oruko, tabi ti okun naa f'oruko jo.

Òkun Índíà: Òkun
Òkun Íńdíà lórí àwòrán ìṣètọ́sọ́nà.



Itokasi

Tags:

AfrikaAsiaIndiaÀgbáyéÒkunÒkun Atlántíkì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

SonyLos AngelesAmsterdamTessalonikaMartin LutherItan Ijapa ati AjaẸ̀sìnGoogleOmikíkanZanzibarFísíksìSantiago10 AugustMassachusettsAdeola OlubamijiLuther VandrossOṣù Kínní 2129 FebruaryLas Vegas8 SeptemberCharlize TheronAbẹ́òkútaSátúrnùAfricaÈdè IrelandỌ̀rọ̀ ìṣeGúúsù ÁfríkàSTS-51-AÀtòjọ àwọn orílẹ̀-èdè Olómìnira àgbáyéFloridaẸ̀sìn IslamRómùÈdè Pẹ́rsíàỌ̀rúnmìlàÈdè ÍtálìTunisiaKonrad AdenauerNamibiaMọfọ́lọ́jì èdè YorùbáSTS-58AlaskaRauf Aregbesola27 SeptemberOjúọ̀run ayéPolinésíà FránsìÀṣà YorùbáAakráOjúewé Àkọ́kọ́Krómíọ̀mùWikipediaSenior Advocate of NigeriaNàìjíríà.guÌgbà SílúríàMaghrebBùrúndìGíríìsìÒgún LákáayéÈdè EsperantoJimmy CarterDonald A. GlaserHirohitoAjéMáltàFránsì13 DecemberLibrary🡆 More