Ìtanná

Ìtanná (Electricity) ni sayensi, imo-ero, onise-ona ati àwon isele eleda to je mo bi awon adijo ina se wa ati bi won se n sanlo.

Itanna n fa orisirisi isele oni-tanna, bi monamona, ina ojukan, ifasara gberingberin onina ati isanlo iwo onitanna ninu waya ina. Bakan naa, itanna gba idasile ati igbasodo iranka gberingberin onina bi awon iru radio laye.

Multiple lightning strikes on a city at night
Monamona je ikan ninu ipa itanna afojuri.

Ninu itanna, awon adijo n se awon papa onigberingberin onina ti won n sise lori awon adijo miiran. Itanna n sele nitori orisirisi awon iru siseeda:

  • adijo itanna: ini awon igbonwo abeatomu melo kan, to unso bi ibasepo onigberingberin onina won yio se ri. Awon elo ti won ti je didijo lonitanna yio je ninipa lori latowo awon papa onigberingberin onina be sini yio tun pese won.
  • iwo itanna: isan awon igbonwo ti won ti je didijo lonitanna, won saba je wiwon ni eyo ampere.
  • papa itanna (e wo isiseojukan onina): iru papa onigberigberin onina agaga kan ti ko soro to je dida latowo adijo itannna kan sibesibe bi ko ti le sún (eyun pe ko si ìwọ́ itanna). Papa itanna unda ipá lori awon adijo miran ti won wa nitosi re. Awon adijo ti won ba unsún na tun unpese papa onigberingberin.
  • iniagbara itanna: eyi ni agbara ti papa itanna ni lati le se ise lori adijo itanna kan, eyi unsaba je wiwon ni volt.
  • àwọn gbéringbérin oníná: iwo initanna unfa papa gberingberin wa, be sini papa gberingberin to unyipada unfa iwo onitanna wa.

Ninu iseero onitanna, itanna unje lilo fun:

  • agbara itanna (eyi le tokasi bi okun iniagbara onitanna ba se posi tabi si okun onitanna larin asiko kan) to wa fun lilo, latodo ile-ise onitanna. Bakanna, "itanna" le je lilo bi oro fun "sisomo waya fun itanna" to tumosi isopomora isise mo ibuso agbara ina. Iru isopomora bahun fun awon alo "itanna" ni aye si papa itanna to wa ninu isopowaya itanna, ati bi be si agbara itanna.
  • isiseonina da lori awon asoyipo onitanna ti won ni awon ohun inu alagbese onitanna bi awon igo adepa, awon tiransisto, awon adojuona ati awon asoyipo olodidi, ati awon oroiseona to ba sepo.

Awon isele onitanna ti je gbigbeka lati igba aye atijo, sibesibe ilosiwaju ninu sayensi re ko sele titi di orundun ketadinlogun ati kejidinlogun. Awon imulo alamuse fun itanna sibesibe si kere, yio si di opin orundun okandinlogun ki awon oniseero o to le lo ni ile-ise ati ibugbe. Igbale iyara ninu oroiseona onitanna ni asiko yi se awon ile-ise ati awujo di otun. Nitoripe itanna se lo lorisirisi ona lati pese okun gba laye mulo ninu opo imulo alainiye bi irinna, igbegbonna, itanmole, ibanisoro, ati isirokomputa. Agbara onitanna ni igbaeyin ile-ise awujo odeoni, be si ni yio ri lojowaju.


Akiyesi

Itokasi

Ajapo ode

Àdàkọ:Wiktionary

Tags:

Electric chargeLightningScienceTechnology

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ẹ̀bùn Àláfíà Nobel2face IdibiaInternet3460 AshkovaWindows 98Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìMethaneEhoroÀsìá ilẹ̀ SìmbábúèMichael JordanÌjọba àìlólóríWikiÈdè LátìnìNajib Tun Razak9 AprilHọ̀ndúràsAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BayoYetunde OdunugaISBNLee TockarZambia22 JuneAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ LereÈdè Gẹ̀ẹ́sìGaza StripYunifásítì KòlúmbíàMons pubisYunifásítì PrincetonISO 3166-1 numericBẹ́ljíọ̀mYukréìnAgbegbe Ijoba Ibile NingiAsiri ọkunrin club (نادي الرجال السري)Kòréà GúúsùESan Jose, Kalifọ́rníàLebanonÒrìṣà EgúngúnLira TúrkìISO 639-2NigerLa MarseillaiseSlofákíàÀsìáMobi OparakuDavid GrossISO 3166Das Schloß (Ìwé)MPlayboi CartiSTS-121Lítíréṣọ̀Ashanti (àkọrin)ParagúáìAfeez OwóEzra OlubiÀwọn Erékùṣù MarshallCotonouÀwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyànẸ̀sìn KrístìYorùbáChioma Wogu🡆 More