Ìgbàjá Àwọn Ìsọ̀gbé Oòrùn Kékeré

Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré jẹ́ àwo róbótó tí ó wà lára ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po, tí ó wà ní bíi àárín ìyípo Mars àti Jupiter.

Àwọn àkórajọ onírúurú tí kò dúró déédé tí wọ́n ń pè ní ástẹ́rọ́ìdì tàbí àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ló gba inú rẹ̀. Wọ́n tún máa ń pe ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ní ojúlówó ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tàbí ojúlówó ìgbàjá lati jẹ́ kí ìyàtọ̀ wá láàárín rẹ̀ àti àwọn míràn tí wọ́n wà lágbo ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po bíi Awon asteroidi itosi Aye ati awon asteroidi troja.

Ìgbàjá Àwọn Ìsọ̀gbé Oòrùn Kékeré
Ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì gbàùngbà (ó hàn pẹ̀lú àwọ̀ funfun) wà láàrin àwọn ìgbàyípo Mars àti Jupiter.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

JupiterMars

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

BitcoinC++Èdè Yorùbá22 Oṣù KẹtaÌbálòpọ̀BeirutCharles MansonBùrúndìWikipediaISO 8601Ògún LákáayéFáwẹ̀lì Yorùbá5 JuneYoichiro NambuIfe Ẹ̀yẹ Àgbáyé FIFA 201017 MayKàlẹ́ndà GregoryFínlándìPolish languageỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Fúnmiláyọ̀ Ransome-KútìFrench languageÀwọn ṢáuángÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáWasiu Alabi PasumaRobert WalpoleAlaskaLítíréṣọ̀ParisiÍrẹ́lándìDavid ToroAtlanta6 Oṣù KẹtaPlatoJosé Gil FortoulIṣẹ́ Àgbẹ̀NATOKelly RowlandÌladò Suez10 MarchGodwin ObasekiKárbọ̀nùMamluk Sultanate (Cairo)BucharestNaijiria2001Ludwig WittgensteinPataki oruko ninu ede Yoruba12 Oṣù KẹtaQuartzNaoto Kan2014 VasilevskisÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìNyma Akashat ZibiriSudanÌran Yorùbá(9981) 1995 BS3KùrìtíbàKunle AfolayanGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè9 MarchChinese languageÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáYasuhiro NakasoneSpéìn🡆 More