Wiki Yorùbá

Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP).

Ojúewé Àkọ́kọ́
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè ÌkòròdúÌpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.

(ìtẹ̀síwájú...)

Ojúewé Àkọ́kọ́

Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹta:

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

  • 1845 – Wilhelm Röntgen, German physicist, Nobel Prize laureate (d. 1923)
  • 1901 – Eisaku Sato, Japanese statesman, recipient of the Nobel Peace Prize (d. 1975)
  • 1970 – Mariah Carey, American pop singer

Àwọn aláìsí lóòní...

  • 1967 – Jaroslav Heyrovský, Czech chemist, Nobel Prize laureate (b. 1890)
  • 1968 – Yuri Gagarin, Soviet cosmonaut (b. 1934)
  • 1981 – Mao Dun, Chinese writer (b. 1895)
Ọjọ́ míràn: 2526272829 | ìyókù...
Ojúewé Àkọ́kọ́

Che Guevara

  • ... pé Ìlú New York kọ́kọ́ jẹ́ pípè bi New Amsterdam?
  • ... pé Guerrillero Heroico (aworan) tó jẹ́ àwòrán Che Guevara ni "fọ́tò tógbajùmọ̀ jùlọ láyé"?
  • ... pé àwọn tóún tẹ̀lé ẹ̀sìn Islam úngbàdúrà ní 5 lójúmọ́?
  • ... pé Mars dà bí pupa nítorí ìdóògún nínú àpáta rẹ̀ àti èruku lójúde rẹ̀?
Ojúewé Àkọ́kọ́
Ojúewé Àkọ́kọ́

Ojúewé Àkọ́kọ́ Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì
Èdè

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Kàlẹ́ndà GregoryPataki oruko ninu ede YorubaFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìOreoluwa LesiÀìsàn inú afẹ́fẹ́Èdè ÍtálìFilniusÀgbàjọOṣù Kínní 9FiennaÌgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeréYerevanÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Pete EdochieC++Ibadan Peoples Party (IPP)KoisaanuDési Bouterse27 JulyXKikan Jesu mo igi agbelebuOxygenÀsìá ilẹ̀ UdmurtiaNẹ́dálándìÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáGúúsù Amẹ́ríkàKánúríAlfred Freddy KrupaẸ̀fúùfùIlé àwọn Aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàSebastián PiñeraÀsìá ilẹ̀ TatarstanOgun Abele NigeriaFẹlá KútìItálíàNamibiaẸgbẹ́ Rẹ̀públíkánì (USA)Samuel Ajayi CrowtherỌjọ́ 18 Oṣù KẹtaNashvilleNigerian People's PartyKing's CollegeAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéNwankwo KanuÌbálòpọ̀Igbeyawo IpaTampereUTCTorontoNiger (country)Ọjọ́ AjéAjagun Ojúòfurufú Amẹ́ríkàÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Òkun GrínlándìMakarios IIIJẹ́ọ́gráfì ilẹ̀ MàláwìJohnny CashTime zoneMike TysonHenry KissingerParisiÈdèÈdè Albáníà25 March🡆 More