Timothy Mofolorunso Aluko (14 June, 1918 - 1 May, 2010) je olukowe ara ile Naijiria.
Aluko jẹ ọmọ yóruba ti à bini Ilesha ni ilẹ naigiria. Arakunrin naa jẹ óriṣiri ipó to si fẹyinti ni ọdun 1978. T. M. Aluko ku ni ọjọ akọkọ, óṣu May ni ọdun 2010 ni ilu èkó.
Aluko naa kẹẹkọ ni College ijọba ni Ibadan ati College ni Yaba, Ipinlẹ Eko lẹyin naa lo lọsi ilè iwè giga ti London lati kẹẹkọ lori Imọ Civil engineering ati town planning. Ni ọdun 1976, Àrakunrin naa gba doctorate lori imọ municipal engineering.
Alukó gba ami ẹyẹ ti OBE ni ọdun 1963 pẹlú ami ẹyẹ ti OON ni ọdun 1964.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article T. M. Aluko, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.