Pílánẹ́tì gẹ́gẹ́ bí i Ẹgbẹ́ìrẹ́pọ̀ ìmọ̀ Òfurufú Káàkiriayé (IAU) ṣe ṣè'tumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ohun òkè-ọrùn tí ó ń yí ìrànwọ́ ká tàbí aloku ọ̀run tí tíwúwosí rẹ̀ jẹ́ kí ó rí róbótó, tí kò tóbi púpọ̀ láti yíyọ́ ìgbónáinúikùn (anthothermonuclear fusion) láàyè nínú rẹ̀, tí ó sì ti gba àwọn oríṣiríṣi ìdènà kúra cartele dé santata lọ́nà tí ó ń gbà kọjá.
Gẹ́gẹ́ bí (IAU) ṣe sọ, pílánẹ́tì mẹ́jọ ni wọ́n wà nínú ètò òòrùn. Àwọn nìwọ̀nyìí bí wọ́n ṣe ń jìnnà sí Òòrùn:
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Plánẹ́tì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.