Owó

Owó ni ohunkóhun tí àwọn ènìyàn kan bá gbà lágbègbè, ìlú tàbí orílẹ̀-èdè wọn láti máa fi ṣe kárakáta ọjà tàbí san gbèsè.

Ó jẹ́ ohunkóhun tàbí àkọsílẹ̀ tó dájú tí gbogbo ènìyàn gbà láti máa fi san owo ọjà rírà, iṣẹ́ tí a ṣe fúnni tàbí san gbèsè àti owó-orí. Àwọn onímọ̀ ṣàlàyé pàtàkì Owó gẹ́gẹ́ bí ohun tí a fi ń ṣe pàṣípàrọ̀ ọ̀jà, nǹkan-ìdíyelọ́jà, nǹkan-ìdíyelé dúkìaí, àti nǹkan ipààlà iye ọjà. Ohunkóhun tí ó bá lè ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí ni a lè kà sí Owó.

Owó
Owó pépà àti kọ́ìsì

Owó nínú ìtàn jẹ́ ohun to tọ́ tí a fi ń ṣe ìdókòwò ọja, àmọ́ ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ wípé owó láyé òde òní ni ónì ètò tó dálé

fiat money. (Owó tí oun tí alè fojú rí bíi góólù tàbí sílífà kòlè rópò)

Fiat money, da bi sowe dowo tabi akosile fun eto isanwo, ko wulo laaye ara re.[citation needed]


Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

Orílẹ̀-èdèỌmọnìyàn

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

R. Lee ErmeyT. M. AlukoErin-Ijesha WaterfallsSevilleMonicazationRoque Sáenz PeñaPonun StelinLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Manuel Benito de CastroIṣẹ́ Àgbẹ̀ISO 9Ìtúká onítítànyindinEhoro.uyOnome ebiWikimediaKikan Jesu mo igi agbelebuNATOEre idarayaGrace AnigbataKentucky.tnPópù Celestine 2kJapan67085 Oppenheimer2 DecemberIrinÀwọn èdè Índíà-Europe9815 MariakirchNnamdi AzikiweAbderamane MbaindiguimÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ BrasilṢàngóEsther OnyenezideÌdíje Wimbledon 1977 − Àwọn Obìnrin ẸnìkanẸ̀bùn Nobel nínú Ìṣiṣẹ́ògùnOwe YorubaÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Côte d'IvoireAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BarutenIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan Nẹ́dálándìFernando Serrano2882 TedescoÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Ẹ́gíptìOrin-ìyìn Orílẹ̀-èdè TransnistriaMenachem BeginFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìOkey BakassiKárbọ̀nùApágúúsù EuropeÒgún LákáayéEuroBalogun MarketMargaret ThatcherLouis St. LaurentSanusi Lamido Sanusi27 JuneIbadan Peoples Party (IPP)Àìsàn ẹ̀jẹ̀ ríruÁntígúàÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Báháráìnì🡆 More