Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì Ilẹ̀ Yugoslafia
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia (Socialist Federal Republic of Yugoslavia; SFRY) je orile-ede Yugoslafia to wa lati igba Ogun Agbaye Keji (1943) titi di igba to je tituka deede ni 1992 larin awon Ogun Yugoslafia.
O je orile-ede sosialisti ati ile apapo to ni awon orile-ede olominira mefa: Bosnia ati Herzegovina, Kroatia, Macedonia, Montenegro, Serbia, ati Slovenia. Serbia, bakanna, tun ni igberiko aladawa meji ti Vojvodina ati Kosovo.
Socijalistička Federativna Republika Jugoslavijaa Социјалистичка Федеративна Република ЈугославијаbSocialistična federativna republika Jugoslavijac Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia Socialist Federal Republic of Yugoslavia
a State name in Serbo-Croatian and Macedonian languages (the name is identical in both), spelled in the Latin alphabet. (See Etymology section for details.) b State name in Serbo-Croatian and Macedonian languages (the name is identical in both), spelled in the Cyrillic alphabet. (See Etymology section for details.) c State name in the Slovene language. Slovene used the Latin alphabet exclusively. (See Etymology section for details.)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.
Itokasi
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ Yugoslafia, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses. ®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.