Orile-ede Olominira Sosialisti ile Kroatia (Socialist Republic of Croatia to unje kikekuru bi SR Croatia; ede Kroatia: Socijalistička Republika Hrvatska, SR Hrvatska) je orile-ede sosialisti ati orile-ede alabagbepo alaselorile ti Orile-ede Olominira Sosialisti Apapo ile Yugoslafia tele.
Socijalistička Republika Hrvatska Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sósíálístì ilẹ̀ Kroatíà Socialist Republic of Croatia | |||||
A federal unit of the Socialist Federal Republic of Yugoslavia | |||||
| |||||
| |||||
Olúìlú | Zagreb | ||||
Èdè oníbiṣẹ́ | ede Kroatia | ||||
Established In the SFRY: - Since - Until | June 13, 1943 June 13, 1943 June 25, 1991 | ||||
Area - Total - Water | Ranked 2nd in the SFRY 56,524 km² 0.227% | ||||
Population - Total - Density | Ranked 2nd in the SFRY 4,784,265 84.6/km² | ||||
Currency | Yugoslav dinar (dinar) | ||||
Time zone | UTC + 1 |
Ohun lo siwaju Orile-ede Olominira ile Kroatia ode oni. O di apa Apapo Toseluarailu Yugoslafia ni 1943. Ni 1990 , o je titundasile bi Kroatia, o gba sistemu egbe oloselu pupo ati okowo oja ainidekun mu (free market economy).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sósíálístì ilẹ̀ Kroatíà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.