Nneka J. Adams

Nneka Julie Adams (tí a bí ní 8 Oṣù Kẹẹ̀jọ) tí a mọ̀ ní akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi Nneka Adams tàbí Nneka J.

Adams jẹ́ Òṣèré ọmọ Nàìjíríà tí ó wà ní ìlu Kánádà, ònkọ̀wé fiimu, ó sì n ṣe fiimu. Orúkọ rẹ̀ tan dáada jùlọ fún àwọn ipa rẹ̀ tó kó nínu àwọn fiimu bí Black Men Rock, Flight Last to Abuja àti Nation Under Siege.

Nneka J. Adams
Ọjọ́ìbíNneka Julie Adams
Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actress, film producer, film writer

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

Adams dagba ní Ìpínlẹ̀ Èkó, àwọn òbi rẹ̀ síì wá láti Ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà. Òun ni èkejì nínu àwọn ọmọ mẹ́fà tí àwọn òbi rẹ̀. Adams lọ sí Ilè-ẹ̀kọ́ gíga Marymount, ó sì lọ sí Yunifásitì ti Ìlú Èkó níbi tí ó ti gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu Ìmòye. Ní àkókò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó bẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò fún àwọn ipò iṣẹ́ ní Nollywood, èyí tó sokùn fa ipa àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ìgbà tówà lómodún mẹ́tàdínlógún (17).

Iṣẹ́ ìṣe

Ó dá ilé-iṣẹ́ Adams film production sílẹ̀, ilé-iṣẹ́ kan tó n rí sí fiimu, tẹlifíṣọ́nu àti ìpolówó. Lórí ilé-iṣẹ́ naà ni ó ti ṣe fiimu, “Black Men Rock” ni ọdún 2017 tó ṣe ìfihàn John Dumel, Ruth Kadiri, Bolanle Ninalowo àti Beverley Osu. Ó tún ṣe fiimu "The Devil in Between" ní èyí tí òun fúnralárarẹ̀, Deyemi Okanlawon àti IK Ogbonna dìjọ kópa nínu rẹ̀. Adams ti hàn nínu àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ fiimu Nollywood. Lára wọn ni Chronicles of Vendata, Ruth, If You Were Mine, Perfect Combo, A Nation Under Siege àti Last Flight to Abuja.

Àkójọ eré

Àwọn Àṣàyàn Eré Rẹ̀

  • The Gentleman
  • His Queen
  • The List
  • Black Men Rock
  • The Devil in Between
  • Ruth
  • Last Flight to Abuja
  • If You Were Mine
  • Chronicles of Vendata
  • A Nation Under Siege

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Nneka J. Adams Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀Nneka J. Adams Iṣẹ́ ìṣeNneka J. Adams Àkójọ eréNneka J. Adams Àwọn ìtọ́kasíNneka J. Adams

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÁrktìkìAfárá Third MainlandẸ̀bùn Ọ́skàPólàndìKurt Georg KiesingerEuropeÈdè ArméníàAndreas SeppiÀmì-ìdámọ̀ kẹ́míkàLong Beach9 AprilÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáṢáínàOwe YorubaṢàngóMain PageMónakòISO 3166Funke AkindeleÀwọn Erékùṣù Marshall.gq2 AprilArméníàÈdè FendaÌbonMichael JordanSunBíbélì Mímọ́LátfíàFally IpupaÌṣèlú ilẹ̀ GuineaIfeYorùbáÀsìá ilẹ̀ FínlándìKíprù.hmAbubakar Olusola SarakiÌsirò StatistikiAustrálíàJide KosokoMyanmarÁfríkàÈdè TàmilMáltàLos AngelesDòmíníkàỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Ìjẹrò-ÈkìtìLeonhard EulerVictoria University of ManchesterÀrún èrànkòrónà ọdún 2019ÀndóràÀṣà YorùbáÈdè Pólándì.uyBerlinAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ LereLíbyàSaint LuciaTajikistan🡆 More