Nigerian People's Party

Ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian Peoples Party (NPP) jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn ẹgbẹ́ẹ́ òṣèlú tí wọ́n ìdíje sípò ase nígbà ìṣèjọba alágbádá ẹ́lẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ẹgbẹ́ òṣèlú yí ni ó jẹ́ àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; àwọn ni Lagos Progressive, Club 19 àti Nigerian Council of Understanding tí gbogbo wọn kalẹ̀ sí Èkó. Lara àwọn tí wọ́n jẹ́ lààmì-laaka inú ẹgbẹ́ òṣèlú náà ni Adeniran Ogunsanya, T.O.S. Benson àti Kola Balogun láti inú ẹgbẹ́ òṣèlú NCNC. Àwọn abẹnugan bíi: Matthew Mbu, Solomon Lar, Omo Omoruyi, Paul Unongo, Antonio Fernandez wá láti inú ẹgbẹ́ The National Council of understanding,nígbà tí Waziri léwájú fún àwọn ẹgbẹ́ Club 19. Lóòtọ́, wọ́n da ẹgbẹ́ òṣèlú yí sílẹ̀ láti díje sípò ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà. Wọ́n da ẹgbẹ́ òṣèlú yí sílẹ̀ láti fi díje dupò Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹgbẹ́ òṣèlú yí ti ní àtìlẹyìn àwọn ìpíe bíi Imo, Rivers ,Plateau ati Èkó pàá pàá jùlọ àwọn Ìpínlẹ̀ apá ìlà Oòrùn. Amọ́, ọ̀gbẹ́ni Waziri fẹ́ di alága àti olùdíje sípò Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian Peool's Party. Gbogbo àwọn abẹnugan inú ẹgbẹ́ òṣèlú náà fa Ààrẹ tẹ́lẹ̀ Nnamdi Azikiwe kalẹ̀ láti díje dupò Ààrẹ fún ẹgbẹ́ òṣèlú náà.

Wọ́n yan àwọn àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn sípò òṣèlú bíi Gómìnà, aṣojú nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin Àti ipò Ààrẹ tí ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ẹgbẹ́ òṣèlú ní Ìpínlẹ̀ Imo. Lara àwọn adìbò yan náà ni Mbakwe nínú ìdìbò tó wáyé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1979. Ẹgbẹ́ òṣèlú yí gbé àwọn ìgbésẹ̀ tó lààmì-laaka ṣáájú kí ìdìbò gbogbo gbò ọdún 1979 tó wáyé. Wọ́n ja Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn tí wọ́n tó 254 kúrò nílò adije dupò òṣèlú, nígbà tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn tí wọ́n jáwé olúborí sí ipò ilé Ìgbómìnà asòfin àgbà jẹ́ ìdá mẹ́tàdínlógún tí wọ́n sì ní Gómìnà mẹ́ta nínú ọmọ ẹgbẹ́ wọn.

Ìṣèlú ìjọba alágbádá ẹlẹ́kejì

Ní Ìṣèlú ìjọba alágbádá ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ẹgbẹ́ òṣèlú National Party of Nigeria (NPN) náa ní àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó pọ̀ jùlọ nílé ìmgbìmọ̀ aṣòfin agbà, èyí mú ìrẹ̀pọ̀ wà láàrín àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú NPP ati NPN tí wọ́n léwájú. Lára àwọn abẹnugan ẹgbẹ́ òṣèlú NPP bíi Ishaya Audu tí ó jẹ́ igbákejì Ààrẹ tí ó ń díje dupò sí ipò Ààrẹ ni wọ́n yan sípò Mínísítà weak hold on the House of Assembly led to an alliance between the NPP and the NPN. The NPP submitted a few candidates for ministerial appointments to consummate the alliance. NPP personalities such as Ishaya Audu, a vice presidential candidate of the party, were selected as ministers. However, the accord hit the rocks in 1981, and Adeniran Ogunsanya, the chairman of the party, asked all ministers to resign; many did not heed his call and some transferred to the NPN.

Àwọn itọ́ka sí

  • Ergun Ozbudun, Myron Weiner; Competitive Elections in Developing Countries, Duke University Press, 1987

Tags:

Adeniran OgunsanyaNnamdi AzikiweNàìjíríàSolomon Lar

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

EthiópíàÌwo Orí ilẹ̀ ÁfríkàISO 3166ISO 639-2Tẹknọ́lọ́jì5 AstraeaPortable Document Format1594 DanjonGánàRọ́síà8762 HiaticulaÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Ata rodoISO 3029Mons pubisSão Tomé and PríncipeIbrahim Babangida.bjToni TonesCharlize TheronSimple Mail Transfer ProtocolGuinea AlágedeméjìLong BeachBaṣọ̀run GáàÀsìá ilẹ̀ AlbáníàṢakíOṣù KẹrinAgbegbe Ijoba Ibile NingiPọ́rtúgàlEto eko ni orile-ede NaijiriaÈdè KánúríHawaiiLítíréṣọ̀KàmbódíàPanamáSTS-121IndonésíàLíktẹ́nstáìnì15 AprilWurldNomba atomuSARS-CoV-2Burkina FasoGoran IvaniševićItan Ijapa ati AjaÀsìá ilẹ̀ Bùrkínà FasòPeso convertible(6103) 1993 HVAMV video formatGuinea TitunÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ àwọn Erékùṣù MarshallIlé àwọn Aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàKim KardashianÀsìá ilẹ̀ SìmbábúèNew Zealand5777 HanakiYemenFransiHans Georg DehmeltSri LankaMyanmar9 October🡆 More