MERINA
Àwọn ti won n so ede wọ̀nyí jẹ́ ará Malayo-Indonesian. Wọ́n ní ìtàn tó gbọ̀ọ̀rìn nípa ìsẹ̀dá wọn ati nipa àṣà àtí ètò òsèlú won láàrin orisi awọn ènìyàn Madagascar. Ẹsin kiriyo ati ẹ̀sìn eranko ni wọn ni sìn
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Merina, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.