Mọ́skò

Mọsko ni olú-ìlú Rọ́síà.

Ìlú nlá ni. Orí odò Moskva ni ó wà. Odún 1918 ni ó di olú-ìlú USSR nígbà tí wón gbé olú-ìlú yìí kúrò ní Leningrad. Moscow ni ìlú tí ó tóbi jù ní Rósíà. Oun ni ó wà ní ipò kefà tí a bá ní kí á ka àwon ìlú tí ó tóbi ní ilé-ayé. Ìlú tí ó léwà ni Moscow. Uspenki Cathedral tí ó wà ní ibè ni wón ti máa n dé àwon tsar (àwon olùdarí Rósíà) lade láyé àtijó. Ibè náà ni Arkhangelski tí wón ti n sin wón wà. Ilé-isé àti Ilé-èko pò ní ibè Lára àwon ilé-èkó ibè ni. Lomonosov University tí ó jé University ìjoba wa ni ibe. Orí òkè Lenin ni wón kó o sí òun sì ni University tí ó tóbi jù ní Rósíà. Ibè náà ni USSR Academy of Sciences wa. Mùsíómù, ilé-ìkàwé àti tíátà wà níbè. Àwon Bolshoi Theatre and Ballet, the State Symphony Ochestra àti the State Folk Dance Company tí ó wà ni Moscow gbayì gan-an ni.

Mọsko
Red Square
Red Square
Area
 • Total1,081 km2 (417 sq mi)
Population
 • Total12,382,754





Itokasi

Tags:

Rọ́síà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Guinea-BissauOlu FalaePierre NkurunzizaÈṣùWikiOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Mao ZedongÈdè Rọ́síàInternetÀkàyéÀjọ àwọn Orílẹ̀-èdèJohn GurdonNigerian People's PartyVictor Thompson (olórin)USAOwo siseIfáẸyẹÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Opeyemi AyeolaÒndó TownAbdullahi Ibrahim GobirÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàWikimediaLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀AfghanístànVictoria University of Manchester2024Ere idarayaIsiaka Adetunji AdelekeItan Ijapa ati AjaOctave MirbeauLọndọnuIlẹ̀ YorùbáC++EuropeMathimátíkìPópù SabinianÀrokòEast Caribbean dollarChris BrownWaterOṣù Kínní 31ÒfinÀríwá Amẹ́ríkàOnome ebiÌlúSheik Muyideen Àjàní BelloÀdírẹ́ẹ̀sì IPSaadatu Hassan LimanOranmiyanWasiu Alabi PasumaBarry WhiteÌpínlẹ̀ Èkó🡆 More