Látfíà

Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv) je orile-ede ni agbegbe Baltiki ni Apaariwa Europe.

O ni bode ni ariwa mo Estonia (343 km), ni guusu mo Lithuania (588 km), ni ilaorun mo Rosia (276 km), ati ni guusuilaorun mo Belarus (141 km). Niwaju Omi-okun Baltiki ni iwoorun ni Swidin wa. Agbegbe Látfíà borile to to 64,589 km2 (24,938 sq mi) o si ni ojuoju tutu kakiri odun.

Republic of Latvia

Latvijas Republika
Orin ìyìn: "God bless Latvia!"  
(Àdàkọ:Lang-lv)
Ibùdó ilẹ̀  Látfíà  (dark green) – on the European continent  (light green & dark grey) – in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Látfíà  (dark green)

– on the European continent  (light green & dark grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Riga
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaLatvian
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
62.1% Latvians
26.9% Russians
  3.3% Belarusians
  2.2% Ukrainians
  5.5% others
Orúkọ aráàlúLatvian
ÌjọbaParliamentary republic
• President
Egils Levits
• Prime Minister
Arturs Krišjānis Kariņš
• Speaker of the Saeima
Ināra Mūrniece
Independence 
• Declared1
November 18, 1918
• Recognized
January 26, 1921
• Soviet occupation
August 5, 1940
• Nazi German occupation
July 10, 1941
• Soviet occupation
1944
• Announced
May 4, 1990
• Restored
September 6, 1991
Ìtóbi
• Total
64,589 km2 (24,938 sq mi) (124th)
• Omi (%)
1.57% (1,014 km2)
Alábùgbé
• 2016 estimate
1,953,200 (148rd)
• 2011 ppl census
2,067,887
• Ìdìmọ́ra
34.3/km2 (88.8/sq mi) (166th)
GDP (PPP)2009 estimate
• Total
$32.234 billion
• Per capita
$14,254
GDP (nominal)2009 estimate
• Total
$26.247 billion
• Per capita
$11,607
Gini (2003)37.7
medium
HDI (2008) 0.866
Error: Invalid HDI value · 48th
OwónínáEuro (EUR)
Ibi àkókòUTC+2 (EET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+3 (EEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù+371
ISO 3166 codeLV
Internet TLD.lv
1 Latvia is de jure continuous with its declaration November 18, 1918.




Itokasi

Tags:

BelarusCountryEstoniaLithuaniaNorthern EuropeRussiaSquare mileSweden

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Eugene O'NeillPakístànOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́New YorkSíńtáàsì YorùbáAkanlo-edeSalvador AllendeYPópù Gregory 16kMẹ́ksíkòỌjọ́ Rú2024OlógbòGúúsù Georgia àti àwọn Erékùṣù Gúúsù SandwichÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒrò àyálò YorùbáÀṣà YorùbáẸyẹOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìOrílẹ̀ èdè AmericaUSAÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbá(213893) 2003 TN2Mons pubisÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÒfinJohn GurdonHugo ChávezAl SharptonÌbálòpọ̀Iṣẹ́ Àgbẹ̀SeattleTẸ̀lẹ́ktrọ́nùÀmìọ̀rọ̀ QRỌ̀rànmíyànLọndọnuOctave Mirbeau28 JuneOṣù KejìPópù Benedict 16kGbólóhùn YorùbáSaadatu Hassan LimanHuman Rights FirstCaliforniaÁsíàJack LemmonRọ́síàÀdírẹ́ẹ̀sì IPBarbara SokyÀwòrán kíkùnDomain Name SystemKàsàkstánÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáÈdèÀrokòEast Caribbean dollarÌpínlẹ̀ ÈkóMurtala MuhammadÀjẹsára Bacillus Calmette–GuérinCalabar🡆 More