Jean-Michel Basquiat (December 22, 1960 – August 12, 1988) je onisona ara Amerika.
O bere bi onisona grafiti ni New York City ni opin ewadun 1970, o si se ni ewadun 1980 aworan kikun Alafarahan-tuntun. Basquiat ku nitori ilokulo heroini ni August 12, 1988, nigba to je omo odun 27.
Jean-Michel Basquiat | |
---|---|
Basquiat (1984) | |
Bíbí | Oṣù Kejìlá 22, 1960 |
Kú | August 12, 1988 Manhattan, New York City, U.S. | (ọmọ ọdún 27)
Ilẹ̀abínibí | American |
Pápá | Painting |
Movement | Postmodern |
Influenced by | Jean Dubuffet, Pablo Picasso, Robert Rauschenberg, Cy Twombly, Andy Warhol |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Jean-Michel Basquiat, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.