77°2′39″W / 38.90000°N 77.04417°W / 38.90000; -77.04417
Àjọ Ètò Owó Káríayé (AEOK; International Monetary Fund, IMF) je agbajo kariaye to n mojuto sistemu inawo lagbaye nipa titele awon ipinu makroekonomi awon orile-ede omo egbe re, agaga awon ipinu to nipa lori osuwon pasiparo owo ati ibamu awon isanwo. O je didasile lati se imuro sinsin awon osuwon pasiparo owo kariaye ati lati segbowo idagbasoke. Oluile-ise re wa ni Washington, D.C., Amerika.
International Monetary Fund | |
---|---|
The official logo of the IMF | |
Type | International organization |
Ibùjókòó | Washington, D.C. United States |
Ọmọẹgbẹ́ | 187 countries |
Managing Director | John Lipsky (acting) |
Main organ | Board of Governors |
Website | http://www.imf.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àjọ Ètò Owó Káríayé, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.