Ikọ́

Ikọ́ jẹ́ ọ̀nà gbígbé atẹ́gùn jáde pẹ̀lú agbára láti ọ̀nà ọ̀fun kí a lè fọ ọ̀nà ọ̀fun náà mọ́ kúrò lọ́wọ́ ìdọ̀tí tí ó sá pamọ́ síbẹ̀.

Ikọ́ wíwú lè jẹ́ lẹ́ẹ̀kan tàbí léra-léra tí yóò sì mú kẹ̀lẹ̀bẹ̀ dání. Wíwúkọ́ léra-léra lè túmọ̀ sí wípé àìsàn tàbí àrùn kan wà ní àgọ́ ara nítorí wípé púpọ̀ lára àwọn àrùn àgọ́ ara ni a lè tàn kálẹ̀ tàbí pin fún ẹlòmíràn

Ṣíṣe ìtọ́jú ikọ́

Ṣíṣe ìtọ́jú ikọ́ nííṣe pẹ̀lú wíwádí ohun tí ó fa ikọ́ fúnra rẹ̀, bí a bá ti mọ̀ọ́n, ìtọ́jú rẹ̀ yóò yá kánkán.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

John LewisNikarágúàÌjọ KátólìkìÀrún èrànkòrónà ọdún 2019GhánàÒgún LákáayéJide KosokoAnnona squamosaeMeitneriomuÀwọn ará Jẹ́mánìWeruche OpiaEwéCreative CommonsMàríà (ìyá Jésù)Osama bin LadenSteve JobsBeninÌwé-òfin Ìbágbépọ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà12 DecemberHassan RouhaniÈdè IrelandRauf AregbesolaWalter BenjaminÀdìtú OlódùmarèBàbàNairobiTanzaniaÀsìá ilẹ̀ AustríàNicosiaÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020TiranaOdunlade Adekola.djAustríà7 AugustÙsbẹ̀kìstánJack PalanceMadridÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020MàláwìAṣọDelamarentulusSátúrnùFIFAAudio Video InterleaveẸrankoImmanuel KantMexicoÈkóMọ́remí ÁjàṣoroÀkúrẹ́Diocletian13 SeptemberSáúdí ArábíàÀṣà YorùbáẸ̀sìnAdeniran OgunsanyaOmi12 OctoberEpoGuinea AlágedeméjìSan FranciscoÀwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn🡆 More