Gúúsù Sudan, lonibise bi Orileominira ile Gúúsù Sudan, je orile-ede tileyika kan ni Ilaorun Afrika.
Juba ni oluilu re. O ni bode mo Ethiopia ni ilaorun; Kenya, Uganda, ati Orileominira Oseluarailu ile Kongo ni guusu; Orileominira Aringbongan Afrika ni iwoorun; ati Sudan ni ariwa.
Republic of South Sudan | |
---|---|
Motto: "Justice, Liberty, Prosperity" | |
Orin ìyìn: "South Sudan Oyee!" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Juba |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English |
Lílò regional languages | Juba Arabic is lingua franca around Juba. Dinka 2–3 million; other major languages are Nuer, Zande, Bari, Shilluk |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Dinka, Nuer, Bari, Lotuko, Kuku, Zande, Mundari, Kakwa, Pojulu, Shilluk, Moru, Acholi, Madi, Lulubo, Lokoya, Toposa, Lango, Didinga, Murle, Anuak, Makaraka, Mundu, Jur, Kaliko, and others. |
Orúkọ aráàlú | South Sudanese |
Ìjọba | Federal presidential democratic republic |
• President | Salva Kiir Mayardit |
• Vice-President | Riek Machar |
Aṣòfin | Legislative Assembly |
Independence from Sudan | |
• Comprehensive Peace Agreement | January 6, 2005 |
• Autonomy | July 9, 2005 |
• Independence from Sudan | July 9, 2011 |
Ìtóbi | |
• Total | 619,745 km2 (239,285 sq mi) (45th) |
Alábùgbé | |
• Estimate | 7,500,000–9,700,000 (2006, UNFPA) 11,000,000–13,000,000 (Southern Sudan claim, 2009) |
• 2008 census | 8,260,490 (disputed) (94th) |
Owóníná | Sudanese pound (SDG) |
Ibi àkókò | UTC+3 (East Africa Time) |
Àmì tẹlifóònù | 249 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Gúúsù Sudan, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.