Gíríìsì

Gíríìsì (English: /ˈɡriːs/  ( listen); Gíríkì: Ελλάδα, Elláda, IPA:   ( listen); Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Ἑλλάς, Hellás, IPA: ), bakanna gege bi Hellas ati fun ibise bi Helleniki Olominira (Ελληνική Δημοκρατία, Ellīnikī́ Dīmokratía, IPA: ), je orile-ede kan ni guusuapailaorun Europe, o budo si apaguusu opin Balkan Peninsula.

Griisi ni ile bode mo Albania, Olominira ile Makedonia ati Bulgaria si ariwa, ati Turki si ilaorun. Okun Aegeani dubule si ilaorun re, the Okun Ioniani si iwoorun, ati Okun Mediterraneani si guusu. Griisi ni o ni etiodo kewa togunjulo ni agbaye toje 14,880 km (9,246.00 mi) ni gigun, ti o ni opolopo iye awon erekusu (bi 1400, 227 ni ibi ti aon eniyan ngbe), ninu won ni Crete, Dodecanese, Cyclades, ati awon Erekusu Ioniani. Bi ogorin ninu ogorun ile Griisi ni o je ti awon oke, ninu ibi ti Oke Olympus ni o gajulo to je 2,917 m (9,570.21 ft).

Orílẹ̀-èdè Olómìnira Hẹ́llẹ́nẹ̀
Hellenic Republic

Ελληνική Δημοκρατία
Ellīnikī́ Dīmokratía
Flag of Gíríìsì
Àsìá
Àmì orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Gíríìsì
Àmì orílẹ̀-èdè
Motto: Eleftheria i Thanatos, (Greek: "Ελευθερία ή Θάνατος", "Freedom or Death") (traditional)
Orin ìyìn: Ὕμνος εἰς τὴν Ἐλευθερίαν
Ýmnos eis tīn Eleftherían
Hymn to Liberty1
Ibùdó ilẹ̀  Gíríìsì  (green) – on the European continent  (light green & grey) – in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Gíríìsì  (green)

– on the European continent  (light green & grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Athens
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGreek
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
94% Greek,
4% Albanian,
2% others
Orúkọ aráàlúGreek
ÌjọbaParliamentary republic
• Ààrẹ
Katerina Sakellaropoulou (Κατερίνα Σακελλαροπούλου)
• Alákóso Àgbà
Kyriakos Mitsotakis (Κυριάκος Μητσοτάκης)
AṣòfinParliament
Modern statehood
• Independence from the Ottoman Empire
25 March 1821
• Recognized
3 February 1830, in the London Protocol
7 May 1832, in the Convention of London
• Current constitution
11 June 1975,
Third Hellenic Republic
Ìtóbi
• Total
131,990 km2 (50,960 sq mi) (96th)
• Omi (%)
0.8669
Alábùgbé
• 2010 estimate
11,305,118 (74th)
• 2011 (preliminary data) census
10,787,690
• Ìdìmọ́ra
85.3/km2 (220.9/sq mi) (88th)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$318.082 billion (37th)
• Per capita
$28,434 (29th)
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$305.415 billion (32nd)
• Per capita
$27,302 (29th)
Gini (2005)33
Error: Invalid Gini value
HDI (2011) 0.861
Error: Invalid HDI value · 29th
OwónínáEuro (€)2 (EUR)
Ibi àkókòUTC+2 (EET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+3 (EEST)
Irú ọjọ́ọdúndd/mm/yyyy
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù30
Internet TLD.gr3
  1. Also the national anthem of Cyprus.
  2. Before 2001, the Greek drachma.
  3. The .eu domain is also used, as in other European Union member states.

Griisi oni fa gbongbo de asa-olaju Griisi ayeijoun, nibi ti gbogbo eniyan gba bi ibusun asa-olaju Apaiwoorun. Nitori eyi o je ibi ibere oseluaralu, imoye Apaiwoorun, Awon Idije Olympiki, litireso Apaiwoorun ati itankiko, sayensi oloselu, awon ipile sayensi ati mathematiki pataki, ati drama, ati trajedi ati awada. Asesile yi han gedegbe ninu awon Ibi Oso Agbaye UNESCO 17 ti won wa ni Griisi.

Griisi je orile-ede adagbasoke to ni Human Development Index giga, Griisi ti je omo egbe Isokan Europe lati 1981 ati Isokan Okowo ati Owonina Europe lati 2001, NATO lati 1952, ati Ile-ise Ofurufu Europe lati 2005. Bakanna o tun je omo egbe latibere Isodokan awon Orile-ede, OECD, ati Agbajo Ifowosowopo Okowo ni Okun Dudu. Atensi ni oluilu re; awon ilu pataki miran nibe tun ni Thessaloniki, Patras, Heraklion ati Larissa.

Awon Periferi ati ibile

Fun amojuto, Griisi ni periferi metala ti won je pipin si ibile mokaleladota ([nomoi] error: {{lang}}: text has italic markup (help), singular Gíríkì: nomos). Bakanna ni agbegbe idawa kan wa to n je Oke Athos (Gíríkì: Agio Oros, "Oke Mimo"), to ni bode mo periferi Central Macedonia.

Map Number Periphery Capital Area (km²) Area (sq mi) Population
Gíríìsì 
1 Attica Athens 3,808 1,470 3,761,810
2 Central Greece Lamia 15,549 6,004 605,329
3 Central Macedonia Thessaloniki 18,811 7,263 1,871,952
4 Crete Heraklion 8,259 3,189 601,131
5 East Macedonia and Thrace Komotini 14,157 5,466 611,067
6 Epirus Ioannina 9,203 3,553 353,820
7 Ionian Islands Corfu 2,307 891 212,984
8 North Aegean Mytilene 3,836 1,481 206,121
9 Peloponnese Kalamata 15,490 5,981 638,942
10 South Aegean Ermoupoli 5,286 2,041 302,686
11 Thessaly Larissa 14,037 5,420 753,888
12 West Greece Patras 11,350 4,382 740,506
13 West Macedonia Kozani 9,451 3,649 301,522
- Mount Athos (Autonomous) Karyes 390 151 2,262




Itoka

Tags:

AlbaniaAmóhùnmáwòrán:En-us-Greece.oggAncient GreekBulgariaCountryEllada.oggEn-us-Greece.oggEuropeMediterranean SeaRepublic of MacedoniaTurkeyen:WP:IPA for Englishen:Wikipedia:IPA for GreekÈdè Gíríkì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ọ́ksíjìnAbẹ́òkútaKrómíọ̀mùRwandaKirgistaniJay-ZÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáMọfọ́lọ́jì èdè YorùbáẸ̀yà ara ìfọ̀13 SeptemberYunifásítìEdward Victor AppletonFidio ereBlaise PascalẸ̀sìn IslamÈdè Ireland.guÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1936Atlanta.prMadonnaAngolaIakoba ItaleliÌmòyeÙsbẹ̀kìstánUfuoma McDermottJoseph ConradQComoros18 DecemberTalcWúràÀgbájọ fún Oúnjẹ àti Iṣẹ́àgbẹ̀Ọ̀rúndún 21kGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèErékùṣù Brítánì OlókìkíFrancisco FrancoInternet Relay ChatLev LandauÈdè FaranséOṣù KejeÒdòdóÈdè Gẹ̀ẹ́sìList of language regulatorsNicosiaFísíksìBanjulÈdè ṢáínàMuhammad ibn Mūsā al-KhwārizmīCornus canadensisGírámà YorùbáJẹ́mánì10 AugustLusakaWikiAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéOrílẹ̀-èdè PalẹstínìImmanuel KantÈdè HúngárìVictoria University of ManchesterSiamunDẹ́nmárkì🡆 More