Físíksì

Físíksì (lati inu Ìmọ̀ aláàdánidá) tabi Fisiki (Physics) jẹ́ ìmọ̀ sáyẹ́nsì tí ó ń ṣe ìwádí èlò ati awon okun ti won n je sise akiyesi ninu àdánidá.

Físíksì

Awon onímọ̀ aláàdánidá n se iwadi isise ati awon ohun-ini eda aye to yi wa ka lati àwọn ẹ̀yà ara ti won n se gbogbo awon elo ti a mo (Ìmọ̀aláàdánidá ẹ̀yà ara, particle physics) titi de bi àgbàlá-ayé se n wuwa bi odidi kan (ìmọ̀ìràwọ̀títò astronomy, ìmọ̀ìdáyé cosmology).

Ise imo aladanida ni lati wa awon ofin ijinle ti gbogbo awon ohun aladanida n tele.

Ko si iye igbedanwo to le fi han pe iro mi je tito, sugbon igbedanwo kan pere le fihan wipe o je aitoAlbert Einstein



Itokasi

Tags:

ÀdánidáÈlò

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Hugo ChávezGoogleAjáThomas CechÌgbéyàwóỌ̀rànmíyànOrílẹ̀Ìsirò StatistikiÌwéVictoria University of ManchesterDoctor BelloÁsíà1117 ReginitaNigerian People's PartyIlẹ̀ Ọba BeninKàlẹ́ndà GregoryYunifásítì HarvardMathimátíkìÈdè YorùbáOctave MirbeauIWaterWikiBeirutẸ̀sìnAderemi AdesojiÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Pópù Benedict 16kEhoroEre idarayaOlódùmarèÒgbóniIni Dima-OkojieBarbara SokyAli Abdullah SalehÒrò àyálò YorùbáCalabarÌṣeọ̀rọ̀àwùjọMyanmarÀríwá Amẹ́ríkàIndonésíàEugene O'NeillSeattleẸranko afọmúbọ́mọAbubakar MohammedÌbálòpọ̀ÒfinGuinea-BissauÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáUSAÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáMao ZedongÈdè FínlándìR. KellyOlógbòOSI modelISO 3166-1 alpha-2Iṣẹ́ Àgbẹ̀🡆 More