Boolu-Afesegba

Bọ́ọ̀lù-àfẹsègbá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn eré-ìdárayá tó ní ṣe pèlú fífi ẹsẹ̀ gbá bọ́ọ̀lù.

Eré-ìdáraya h yìí pẹ̀ka sóríṣiríṣi ọ̀nà, ara rẹ̀ la ti rí association football, gridiron football tàbí American football tàbí Canadian football, Australian rules football, rugby union pẹ̀lú rugby league àti Gaelic football. Oríṣi ẹ̀ka bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá wọ̀nyí ní nǹkan tó pa wọ́n pọ̀, tí a mọ̀ sí kóòdù bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá

Boolu-afesegba
Boolu-Afesegba
An attacking player (No. 10) attempts to kick the ball past the goalkeeper and between the goalposts to score a goal
Highest governing bodyFIFA
Nickname(s)Football, soccer, futbol, footy/footie, "the beautiful game"
First playedMid-19th century England
Characteristics
ContactYes
Team members11 per side
Mixed genderYes, separate competitions
CategorizationTeam sport, ball sport
EquipmentFootball
VenueFootball pitch
Olympic1900
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Boolu-Afesegba
Several codes of football. Clockwise from top left: association, gridiron, rugby union, Gaelic, rugby league, and Australian rules

Oríṣiríṣi ìtọ́kasí ló wà fún bọ́ọ̀lù ìbílẹ̀ tí wọ́n ń gbá káàkiri àgbááyé. Ó sì ní òfin tó de wọ̀n, àwọn òfin yìí ti wà láti sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún. Ìtànkálẹ̀ British Empire mú kí àwọn òfin yìí tàn káàkiri eré náà.

Ní ọdún 1888, wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ The Football League ní England, èyí sì jẹ́ ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá alámọ̀dájú àkọ́kọ́. Ní sẹ́ńtúrì ogún, ọ̀pọ̀lọpọ̀ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá lọ́ríṣiríṣi wá di ìlú-mọ̀ọ̀nká, tí wọ́n sì ń gbá káàkiri orílẹ̀-èdè ní àgbááyé.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

American footballAssociation football

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Adeniran Ogunsanya College of Education67085 OppenheimerISO/IEC 7810Joel McHaleTwitterISO/IEC 8859-8Sístẹ̀mù ÒrùnISO 31-12Charles Glover BarklaISO/IEC 8859-12InternetCelestial Church of ChristAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ IpokiaISO 1413.egFuel oilIsaac NewtonFidio ereOggISO 14644-3ÒjòISO 31-13ISO 428ISO 31-0ISO/IEC 7813ISO/IEC 27004H.264/MPEG-4 AVCISO 2788Chantal YoudumISO 10160.mnÀsìá ilẹ̀ ÍslándìISO 11992Àdìtú OlódùmarèAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ MatazuBostonSVOPCTáyọ̀ AwótúsìnÌtànÈdè LárúbáwáISO 27799PólándìAgbegbe Ijoba Ibile Ariwa AfikpoÀjẹsára àrùn onígbáméjìCatherine Zeta-JonesHypertext Transfer ProtocolGbẸ̀gbà ỌrùnISO/IEC 9995Kòréà GúúsùNàìjíríàISO 3166-3Àwo Àlẹ̀mọ́lẹ̀Claire TrevorISO 639-616 JuneISO/IEC 8859-1BáháráìnìLíbyàJohann Wolfgang von Goethe918 IthaBobriskyÍndíàỌjọ́AṣọClarion Chukwura.tt.bgISO/IEC 8859-9Titun Mẹ́ksíkò🡆 More