Bùrúndì

Bùrúndì (pipe /bəˈɹʊndɨ/), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì (Kirundi: Republika y'u Burundi, ; Faransé: République du Burundi, ), je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon Adagun Ninla ni Apailaorun Afrika to ni bode mo Rwanda ni ariwa, Tanzania ni ilaorun ati guusu, ati Orile-ede Olominira Oloselu ile Kongo ni iwoorun.

Oluilu re ni Bujumbura. Botilejepe orile-ede na je ademolesarin, opo bode re ni apa guusuiwoorun wa niwaju Adagun Tanganyika.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì
Republic of Burundi  (English)

Republika y'u Burundi  (Kirundi)
République du Burundi  (Faransé)
Motto: "Ubumwe, Ibikorwa, Iterambere"  (Kirundi)
"Unité, Travail, Progrès"  (Faransé)
"Ọ̀kan, Iṣẹ́, Ìrewájú"
"Unity, Work, Progress" 1
Orin ìyìn: Burundi bwacu
(Our Burundi)
Ibùdó ilẹ̀  Bùrúndì  (dark blue) – ní Africa  (light blue & dark grey) – in the African Union  (light blue)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Bùrúndì  (dark blue)

– ní Africa  (light blue & dark grey)
– in the African Union  (light blue)  —  [Legend]

OlùìlúBujumbura
Ìlú tótóbijùlọolúìlú
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaKirundi
Faransé
Àwọn èdè ìbílẹ̀Kirundi, Swahili
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
Hutu 85%
Tutsi 14%
Twa 1%
Orúkọ aráàlúará Bùrúndì
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira
• Ààrẹ
Évariste Ndayishimiye
• Igbákejì Ààrẹ 1k
Prosper Bazombanza
• Igbákejì Ààrẹ 2k
Gervais Rufyikiri
AṣòfinIléaṣòfin
• Ilé Aṣòfin Àgbà
Ilé Alàgbà
• Ilé Aṣòfin Kéreré
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
• látọwọ́ Ibi-ilẹ̀ Ìdìmú UN tí Bẹ́ljíọ́m sàmójútó
July 1, 1962 (UN Trust Territory) and July 1, 1966 (Independence of the Republic)
Ìtóbi
• Total
27,834 km2 (10,747 sq mi) (145th)
• Omi (%)
7.8
Alábùgbé
• 2012 estimate
8,749,000 (89th)
• 2008 census
8,053,574
• Ìdìmọ́ra
314.3/km2 (814.0/sq mi) (45th)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$5.184 billion
• Per capita
$614
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$2.356 billion
• Per capita
$279
Gini (1998)42.4
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.282
Error: Invalid HDI value · 166th
OwónínáBurundi franc (FBu) (BIF)
Ibi àkókòUTC+2 (CAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́ọ̀tún
Àmì tẹlifóònù257
ISO 3166 codeBI
Internet TLD.bi
  1. Before 1966, "Ganza Sabwa".
  2. Estimate is based on regression; other PPP figures are extrapolated from the latest International Comparison Program for benchmark estimates.

Awon Twa, Tutsi, ati Hutu ni won ti ungbe ni Burundi latigba ti orile-ede na ti je didasile ni orundun marun seyin. Burundi je jijoba lelori bi ileoba latowo awon Tutsi fun ogorun meji odun. Sugbon latibere orundun ogun Jemani ati Belgium gba ori ibe won si so ibe di ileamusin to ruko re unje Ruanda-Urundi.

Cobalt ati baba ni meji ninu awon ohun alumoni ti Burundi ni. Bakanna Burundi unta kofi ati suga.

Àwọn ìpínlẹ̀ ìjọba

Burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko 18, 117 communes, and 2,638 collines (hills). Provincial governments are structured upon these boundaries. In 2000, the province encompassing Bujumbura was separated into two provinces, Bujumbura Rural and Bujumbura Mairie. The newest province, Rumonge, was created on 26 March 2015 from portions of Bujumbura Rural and Bururi.

Itokasi

Tags:

BujumburaDemocratic Republic of the CongoRwandaTanzaniaen:Help:IPA/Frenchen:WP:IPA for English

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Donald TrumpFiennaGeorgiaMarseilleAbdullahi Umar GandujeÌránìAfárá Third MainlandAlbert EinsteinÈdè iṣẹ́ọbaỌbàtáláOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sósíálístì ilẹ̀ YugoslafiaISO 8601Ike EkweremaduÈdè InterlinguePennsylvania6 JuneÙsbẹ̀kìstánSurulereErin-Ijesha WaterfallsLebanonStephanie Okereke LinusSeun KutiWikisourceKánádàRoman EmpireDiamond JacksonAlfred HitchcockSáyẹ́nsìJürgen HabermasÌṣekọ́múnístìJẹ́ọ́gráfìCharles Albert GobatList of heads of state of MexicoỌmọnìyànBeirutÀṣà YorùbáÌwéCheryl Chase (activist)ShintoÁrgọ̀nùỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Họ̀ndúràsKunle Afolayan.jpGeorge ReadJean-Paul SartreAmenhotep IIÈdè Bẹ̀ngálìIrinJunichiro KoizumiIléMọfọ́lọ́jì èdè YorùbáÀdánidáMaliÈṣùArabic languageỌdúnÀlgéríàÈdè AzerbaijaniAlphonse Hercule MatamGbenga OloukunTwiÍónìÀrùn oorun àsùnjùTehranMẹ́kkàTwitterFrédéric PassyLeonard CohenDas Schloß (Ìwé)Àrokò🡆 More