Assyria

Assyria ni ile-oba to gbale si Oke odo Tigris, ni Mesopotamia (Iraq), to joba lori awon opo ile obaluaye lopo igba.

Oruko re wa lati oruko oluilu re akoko eyun ilu ayeijoun Assur (Akkadian: [𒀸𒋗𒁺 𐎹 Aššūrāyu] error: {{lang}}: text has italic markup (help); Arabiki: أشور [Aššûr] error: {{lang}}: unrecognized language tag: arLatn (help); Heberu: אַשּׁוּר Aššûr, Aramaic: ܐܫܘܪ Ašur. Bakanna Assyria tun le je agbegbe jeografi tabi inu ibi ti awon ile obaluaye wonyi wa.

Assyria
Map of the Neo-Assyrian Empire and its expansions.
Ancient
Mesopotamia
Euphrates · Tigris
Sumer
Eridu · Kish · Uruk · Ur
Lagash · Nippur · Ngirsu
Elam
Susa · Anshan
Akkadian Empire
Akkad · Mari
Amorites
Isin · Larsa
Babylonia
Babylon · Chaldea
Assyria
Assur · Nimrud
Dur-Sharrukin · Nineveh
Hittites · Kassites
Ararat / Mitanni
Chronology
Mesopotamia
Sumer (king list)
Kings of Elam
Kings of Assyria
Kings of Babylon
Mythology
Enûma Elish · Gilgamesh
Assyrian religion
Language
Sumerian · Elamite
Akkadian · Aramaic
Hurrian · Hittite

Nigba Assyria Atijo (awon orundun 20th de 15th BCE), Assur joba lori opo Mesopotamia Loke ati awon apa Asia Minor. Nigba Asiko Arin Assyria (awon orundun 15th de 10th BCE), ipa re resile gidigidi sugbon o fi ija gba won pada. Ile Obaluaye Assyria Tuntun ti Igba Ibere Irin (911 – 612 BCE) fe si gidigidi, be sini labe Ashurbanipal (r. 668 – 627 BCE) fun awon odun ewa o joba lori Ayipo Olora, ati Egypt, ko to bo sowo Babiloni Tuntun ati Medes ki awon eleyi na o to bo sowo Ile Obaluaye Persia.

Itokasi

Tags:

Arabic languageAramaic languageHebrew languageIraq

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÁrktìkìLee TockarAsaba, NàìjíríàỌdẹCristiano RonaldoCoat of arms of QatarLebanon108 HecubaFally IpupaYunifásítì HarvardAlexander MackenzieEwìÒkè OlúmọÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ SíríàJessica TandyIfáMichelle ObamaDubaiGánàVicente FernándezASíríàAfárá Third MainlandKàsínòOjukokoroÒrò àyálò YorùbáAlaskaAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ LereÍslándìRamsey NouahDòmíníkàÀrokòROrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin ÁfríkàIlú-ọba Ọ̀yọ́Yunifásítì ìlú ÈkóṢìkágòNigerian People's PartyÀwọn Erékùṣù SpratlyAdeniran OgunsanyaSri LankaBòtswánàTwitterEpoErékùṣùNational Basketball AssociationIṣẹ́ Àgbẹ̀Gregor MendelMons pubisISO 3166Àkójọ àwọn olúìlú orílẹ̀-èdè ní Europe gẹ́gẹ́ bíi ààlàTẹknọ́lọ́jìÈdè TúrkìAalo ilé àti olorunAdolf Hitler.bhNauruMyanmarSingaporeFloridaSan MàrínòÁsíàBẹ́ljíọ̀mEfikOrílẹ̀-èdè PalẹstínìMoldovaỌba AbdulRasheed Adéwálé Àkànbí🡆 More