Arméníà (i /ɑrˈmiːniə/; Arméníà: Հայաստան, siso Hayastan, IPA: ), fún iṣẹ́ọba bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Arméníà (Հայաստանի Հանրապետություն, Hayastani Hanrapetut’yun, ), je orile-ede oke-ile ti ile yika ni agbegbe Kafkasu ni Eurasia.
O budo si oritameta Apaiwoorun Asia ati Apailaorun Europe, o ni bode mo Turki ni iwoorun, Georgia ni ariwa, de facto Nagorno-Karabakh Republic alominira ati Azerbaijan ni ilaorun, ati Iran ati ile Azerbaijani Nakhchivan ni guusu.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Arméníà Republic of Armenia
| |
---|---|
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Yerevan 40°11′N 44°31′E / 40.183°N 44.517°E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Armenian |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2011) |
|
Ẹ̀sìn | Armenian Apostolic Church |
Orúkọ aráàlú | Armenian |
Ìjọba | Unitary parliamentary republic |
• President | Vahagn Khachaturyan (Վահագն Խաչատուրյան) |
• Prime Minister | Nikol Pashinyan (Նիկոլ Փաշինյան) |
• President of the National Assembly | Alen Simonyan (Ալեն Սիմոնյան) |
Aṣòfin | National Assembly |
Establishment history | |
• Orontid dynasty | 6th century BC |
• Kingdom of Greater Armenia united under the Artaxiad Dynasty | 190 BC |
• Arsacid dynasty | 52–428 |
• Bagratid Armenia | 885–1045 |
• Kingdom of Cilicia | 1198–1375 |
• First Republic of Armenia declared | 28 May 1918 |
1936-1991 | |
• Independence from the Soviet Union | 21 September 1991 |
Ìtóbi | |
• Total | 29,743 km2 (11,484 sq mi) (138th) |
• Omi (%) | 4.71 |
Alábùgbé | |
• 2020 estimate | 2,956,900 ▼ (137th) |
• 2011 census | 3,018,854 ▼ |
• Ìdìmọ́ra | 101.5/km2 (262.9/sq mi) (99th) |
GDP (PPP) | 2019 estimate |
• Total | $32.893 billion |
• Per capita | $10,995 |
GDP (nominal) | 2019 estimate |
• Total | $13.444 billion (127th) |
• Per capita | $4,527 (104th) |
Gini (2018) | Àdàkọ:IncreaseNegative 34.4 medium |
HDI (2018) | ▲ 0.760 high · 81st |
Owóníná | Dram (֏) (AMD) |
Ibi àkókò | UTC+4 (AMT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +374 |
ISO 3166 code | AM |
Internet TLD |
|
45°E / 40°N 45°E
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Arméníà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.