Alibéníà

Alibéníà (i /ælˈbeɪniə/ al-BAY-nee-ə, Àdàkọ:Lang-sq, Gheg Albanian: Shqipnia/Shqypnia), lonibise bi Orileominira ilẹ̀ Alibéníà (Àdàkọ:Lang-sq, pipe Àdàkọ:IPA-sq; Gheg Albanian: Republika e Shqipnísë), je orile-ede ni Guusuilaorun Europe, ni agbegbe awon Balkani.

O ni bode mo Montenegro ni ariwailaorun, Kosovo[a] ni riwailaorun, Orileominira ile Makedonia ni ilaorun ati Girisi ni gusu ati gusuilaorun. O ni eti-omi ni egbe Omi-okun Adriatiki ni iwoorun, ati legbe Omi-okun Ionia ni gusiiworun. O fi iye to din ni 72 km (45 mi) jinna si Italy, nikoja Strait of Otranto to ja Adriatic Sea po mo Ionian Sea. Albáníà je omo egbe UN, NATO, Agbajo fun Abo ati Ifowosowopo ni Europe, Igbimo ile Europe, Agbajo Owo Agbaye, Agbajo Ipade Onimale be sini omo egbe lati ibere Isokan fun Mediteraneani. Albania ti fe di omo egbe Isokan Europe lati January 2003, be sini o ti toro lati di omo egbe lati 28 April 2009.

Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Albáníà
Republic of Albania

Republika e Shqipërisë
Orin ìyìn: [Himni i Flamurit] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  
Hymn to the Flag
Ibùdó ilẹ̀  Alibéníà  (green) on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Alibéníà  (green)

on the European continent  (dark grey)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Tirana
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaAlbanian1
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
92% Albanians,
6% Greeks, 2% others
Orúkọ aráàlúAlbanian
ÌjọbaOrílẹ̀òmìnira oníléaṣòfin
• Ààrẹ
Ilir Meta
• Alákóso Àgbà
Edi Rama
Formation
• Principality of Arbër
1190
• League of Lezhë
2 March 1444
• Independence from the Ottoman Empire
28 November 1912
• Recognized by the Great Powers
2 December 1912
• Current Constitution
28 November 1998
Ìtóbi
• Total
28,748 km2 (11,100 sq mi) (143rd)
• Omi (%)
4.7
Alábùgbé
• 2010 estimate
3,195,000 (136th)
• 2001 census
3,069,275
• Ìdìmọ́ra
111.1/km2 (287.7/sq mi) (63)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$23.864 billion
• Per capita
$7,453
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$11.773 billion
• Per capita
$3,677
Gini (2005)26.7
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.719
Error: Invalid HDI value · 64th
OwónínáLek (ALL)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (CEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù355
ISO 3166 codeAL
Internet TLD.al
  1. Greek, Macedonian and other regional languages are government-recognized minority languages.

Albáníà je oseluarailu onileasofin pelu itokowo toun yipada. Oluilu Albáníà, Tirana, je ile fun awon eniyan bi 600,000 ninu awon eniyan 3,000,000 to wa lorile-ede na. Atunse oja alominira ti si orile-ede sile fun inawo idagbasoke latokere, agaga fun idagbasoke okun ati eto irinna.

Itokasi

Tags:

Council of EuropeEuropean UnionFáìlì:En-us-Albania.oggGbígbọ́GreeceItalyKosovoMontenegroNATORepublic of Macedoniaen:Wikipedia:IPA for Englishen:Wikipedia:Pronunciation respelling key

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

PlatoEre idarayaInternetOghara-IyedeHenri PoincaréISO 3166-1Kelly Rowland28 DecemberEden HazardAnton ChekhovÈdè Gẹ̀ẹ́sìOṣù Kínní 12YorùbáÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáOlómìnira Nagorno-KarabakhTajudeen Oyèwọlé (Abìjà)BeirutFúnmiláyọ̀ Ransome-KútìPonnaIfáIfe Ẹ̀yẹ Àgbáyé FIFA 2010TelluriumLíbyàẸkún ÌyàwóKúbàMọ́remí ÁjàṣoroSudanÀrùn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn Ebola22 Oṣù KẹtaNaijiriaMaryam YahayaParisiSalvador DalíCristiano RonaldoAtlantaYasuhiro NakasoneVladimir PutinVladimir LeninAlan ShepardÀríwá Áfríkà7 Oṣù KẹtaÈdè YorùbáÀsà ilà kíkọ ní ilé YorùbáNgozi Okonjo-Iweala13 OctoberYukréìn20 April4 MarchÌladò SuezOyinyechi ZoggLeonid BrezhnevOgun Abele Nigeria14 Oṣù KẹtaÀrokòOṣù Kẹta30 March2023Ìtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáAkanlo-edeAGerald FordKánádàFránsìAlaska🡆 More