Alákàn tàbí Akàn tí wọ́n ń dà pè ní decapod ní èdè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ ẹranko tí ó lè gbé lórí ilẹ̀ àti inú omí.
Taxonomy not available for Brachyura; please create it automated assistant
(Gíríkì: βραχύς = short, οὐρά / οura = tail) Ẹranko yí ma ń gbé nínú pàlà pálá ihò ilẹ̀ tàbí abẹ́ àwọn ewéko ní etí omi. Bákan náà ni kò sí ibi tí wọn kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé pátá.
Crab | |
---|---|
Grey swimming crab Liocarcinus vernalis | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Sections and subsections | |
|
Alákàn jẹ́ ẹranko tí gbogbo egungun ara rẹ̀ wà ní ìta tí àwọn ẹran rẹ̀ sì sá pamọ́ sí inú ihò egungun ara rẹ̀. Ó sábà ma ń ní ẹsẹ̀ mẹ́fà; mẹ́ta lọ́tùn ún mẹ́ta lósì, bẹ́ẹ̀ ni ó ní kiní kan bí ìlédìí kọ̀kan lọ́tún àti lósì, tí ó sì tún ní ọwọ́ méjì níwájú tí ọwọ́ náà sì tún ní ẹ̀mú (pincer) tí ó fi ma ń dáàbò bo ara rẹ̀ lọ́wọ́ ewu.
Oríṣríṣi akàn tí ó wà ni ó ní orúkọ tí wọ́n ń oè wọ́n ní agbègbè tí wọ́n bá wà ní orílẹ̀ àgbáyé. Lára orúkọ àti oríṣi akàn tí ó wà ni:
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Alákàn, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.