Èdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-Orúkọ

Ọ̀rọ̀ orúko ni ọ̀rọ̀kọrọ̀ nínú gbólóhùn èdè Yorùbá tí ó jẹ́ orúkọ tàbí tí ó ń tọ́ka sí orúkọ ènìyàn, ẹranko, ìlu, nǹkan (ẹlẹ́mìí tàbí aláìlẹ́mìí, nǹkan afòyemọ̀, nǹkan aṣeékà, aláiseéka ) ọ̀rọ̀ orúkọ ni olùwà fún àbọ̀ .


Àwọn Àpẹẹrẹ Ọ̀rọ̀-Orúkọ

*Bọ́lá, Shadè, Adé wálé - Ọ̀rọ̀-Orúkọ Ènìyàn *Ewúrẹ́, Ajá, - Ọ̀rọ̀-Orúkọ Ẹranko *Òkúta, Tábìlì, ìwé,- Ọ̀rọ̀-Orúkọ Nǹkan   Aláìlẹ́mìí *ènìyàn, ẹranko - Ọ̀rọ̀-Orúkọ Nǹkan Ẹlẹ́mìí *Ìfẹ́,ìbànújẹ́ - Ọ̀rọ̀-Orúkọ Afòyemọ̀ *Èkùrọ́ tábìlì - Ọ̀rọ̀-Orúkọ aṣeékà *Omi, ìrẹsì - Ọ̀rọ̀-Orúkọ Àìṣeékà.  

Àpẹẹrẹ lílò:

Bọ́lá wọ aṣọ.

Ewúré ni mo pa.

Ìpò tí Ọ̀rọ̀-Orúkọ máa ń wà nínú gbólóhùn èdè Yorùbá

Ipò méjì pàtàkì ni ọ̀rọ̀ orúkọ lè wà lédè Yorùbá. Ó lè wà nípò olùwà tàbí nípò àbọ̀.

Ọ̀rọ̀-Orúkọ lédè Yorùbá lè wà ní ipò olùwà. Bí àpẹẹrẹ; Bọ́lá lọ jẹun.

Ọ̀rọ̀-Orúkọ lédè Yorùbá lè wà nípò àbọ̀. Bí àpẹẹrẹ; Ṣadé ra bàtà.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

Èdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-Orúkọ Àwọn Àpẹẹrẹ Ọ̀rọ̀-OrúkọÈdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-Orúkọ Àpẹẹrẹ lílò:Èdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-Orúkọ Ìpò tí Ọ̀rọ̀-Orúkọ máa ń wà nínú gbólóhùn èdè YorùbáÈdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-Orúkọ Àwọn Ìtọ́kasíÈdè Yorùbá Ọ̀rọ̀-Orúkọ

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO 639-1ISO 31000David CameronOgun Àgbáyé KìíníKikan Jesu mo igi agbelebuRáràJoseph GoebbelsEdward Adelbert DoisyISO 10962KopernisiomuZheng HeVolleyballÀwo Àlẹ̀mọ́lẹ̀Nọ́rwèyJBIGInternational Standard Book NumberÒjòÈdè EfeKòréà GúúsùÀjẹsára àrùn onígbáméjìJohn Lewis.meÌṣèlú ilẹ̀ GuineaẸkún ÌyàwóAbrahamuComputer Graphics MetafileISO 3166-1Johann Wolfgang von GoetheSVOPCAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ MatazuFulgencio BatistaISO/IEC 9995ISO/TR 11941ISO 14000ISO 14698OlógbòKing's College, LagosJames ScullinṢàngóISO 10161Àrúbà2022ISO 10006BrusselsClarion ChukwuraUSAISO 2788ISO 10383Biodun JeyifoISO/IEC 8859-9Baskin-Robbins.inISO 19092-2Adeniran Ogunsanya College of EducationDavid WoodardEpoChantal YoudumAmina BilaliIṣẹ́ Àgbẹ̀Táyọ̀ AwótúsìnMons pubisISO 15897135 filmDẹ́nmárkìIrinAkira Suzuki (chemist)ISO/IEC 20000Onitsha.am🡆 More