Òdòdó, ti a mo nigba miran bi ìtànná ewéko, ni eyi to ni ibi atunbi ninu awon ogbin olododo (awon ogbin ti a mo si Magnoliophyta, tabi angiosperms).
Ise aaye ododo ni lati kopa ninu atunbi nipa wiwa ona lati mu omiepon wa ba awon eyin.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Òdòdó, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.