Òṣèlú

Òṣèlú je ijoba ìṣèlú ará ìlu boya to ba wa taara lati owo awon ara ilu tabi ki won fun awon asoju won lase ninu idiboyan lati lo agbara yi.

Àwon elédè Gèésì n pèé ní democracy to wa lati inú ede Griiki: δημοκρατία - (dēmokratía) tí ó tumo si "agbara aralu" eyi ti won yi wa lati δῆμος (dêmos), "aralu" ati κράτος (krátos) "agbara" larin orundun ikarun-ikerin kJ lati toka si iru ìlànà oselu to wa nigba náà ni awon ilu orile-ede Grisi, pataki ni Ateni Atijo leyin rogbodiyan odun 508 kJ.

Òṣèlú




Itokasi

Tags:

ElectionGreeceGreek languageIjobaPolitics

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Coordinated Universal Time1 NovemberMassachusetts.guÍndíàOrúkọ ìdíléC++New ZealandDar es SalaamÀgbájọ fún Oúnjẹ àti Iṣẹ́àgbẹ̀Ilẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnEukaryoteEthiopiaAdekunle Gold7 AugustOjúọ̀run ayéOṣù KẹtaJimmy CarterMọ́skò27 August.djOsama bin LadenGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèRichard NixonAnígunmẹ́ta6 MarchObìnrinWalter BenjaminJacques MaritainAMadridFriedrich EngelsLibyaOpen AustrálíàAfricaEzra OlubiCreative CommonsAma Ata AidooSátúrnùAkanlo-edeJack PalanceÀwọn Erékùṣù MarshallÌwéEpisteli sí àwọn ará FílíppìIndonésíàÀgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págunÀwọn Ìdíje Òlímpíkì9 FebruaryẸ̀sìnIlẹ̀ọbalúayé AustríàChristian BaleKàlẹ́ndà GregoryFacebookJean-Paul Sartre16 July10 MarchÌṣọ̀kan ÁfríkàAngolaAgaricocrinusMaryam YahayaAgbègbè àkókòArméníàÙsbẹ̀kìstán27 SeptemberLima🡆 More