GNU Free Documentation License (GFDL) (Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU) jẹ́ ìwé àṣẹ copyleft fún aṣàlàyé ọ̀fẹ́ látọwọ́ Free Software Foundation (FSF) fún àwọn iṣẹ́ ọwọ́ GNU.
Àtẹ̀jáde 1.3 ni ó wà lọ́wọ́, ìkọ oníbiṣẹ́ rẹ̀ ṣe é rí ní àdírẹ́sì http://www.gnu.org/copyleft/fdl.html.
Ìwé àṣẹ náà wà fún aṣàlàyé atòlànà kọ̀mpútà àti bákanáà fún àwọn ìjésì míràn àti fún àwọn ìwé ìlànà. Èyí mudájú pé àwòkọ kọ̀ọ̀kan èlò náà, bótilẹ̀jẹ́ láláàtúnṣe, yíò ní ìwé àṣẹ kannáà. Àwọn àwòkọ wọ̀nyí ṣe é tà, sùgbọ́n eni tó tà gbọdọ̀ mọ̀ pé elòmíràn náà lè ṣe àtúnṣe síi láì gbàṣẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Wiki ni iṣẹ́ ọwọ́ tótóbijùlọ aṣàlàyé ọ̀fẹ́ tó únlo ìwé àṣẹ yìí.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ìwé Àṣẹ Aṣàlàyé Ọ̀fẹ́ GNU, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.