Ìrẹsì jẹ́ èso irúgbìn ohun ọ̀gbìn tí gbogbo ènìyàn ma ń jẹ jákè-jádò orílẹ̀ àgbáyé, pàá paa jùlọ ní ilẹ̀ Asia.
Ohun ọ̀gbìn yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ohun ọ̀gbìn óúnjẹ tí wọ́n pèsè jùlọ ní àgbáye ní iye ( 741.5 mílíọ́nù tọ́ọ̀nù ní ọdún 2014), lẹ́yìn Ìrèké àti àgbàdo.
Nígbà tí wọ́n ma ń lo ìrèké àti àgbàdo fún ìpèsè oríṣríṣi nkan, yàtọ̀ sí jíjẹ lásán bíi ti ìrẹsì.
Oríṣríṣi ìrẹsì ló wà, irúfẹ́ èyí tí ó bá hù ní agbègbè kan ma ń dá lórí ilẹ̀ àti ojú ọjọ́ agbègbè náà.
.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ìrẹsì, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.